YO/Prabhupada 0320 - We are Teaching How to Become Bhagyavan, Fortunate



Lecture on BG 16.6 -- South Africa, October 18, 1975

Omo-obirin: Śrīla Prabhupāda, Gbogbo awon eda je nkankan pelu Olorun. tawa o bale teriba fun Krsna ninu aye tawayi, tobaya gbogbo wa asi teriba fun.

Pusta Krsna: Se gbogbo eyan ma teriba fun Krsna ninu aye yi, se gbogbo wa ma teriba fun Krsna? Se gbogbo wa ma pada si ijoba Orun?

Prabhupada: Hm? Se eyin ni ikanju kankan? Nkan to wa nipw kon se gbogbo eyan loma lo. Ema je ko dayin laamu. Gbogbo eyna ko lom alo Nitorina ni Caitanya Mahāprabhu se sowipe, ei rūpe brahmāṇḍa bhramite kona bhāgyavān jīva (CC Madhya 19.151). Afi teyan ba je bhāgyavān, eni to sorire gan, kole pada lo si ijoba ortun. Oma jera sibi. Itumo egbe imoye Krsna yi ni wipe afe ki awon eyan di bhāgyavān toba fe o le di bhāgyavān. Ise wa niyen. Ati si awon ile-adura to po. asi n'ko awon eyan lati di bhāgyavān, kon sorire, kon ba le pada si ijob aorun, bonsele ni idunu. Nisin, teyan ba sorire, wan gba ilan wanyi, wansi yi aye wan pada. Ise apifunni re niyen. Sugbon tawan eyan o ba di bhāgyavān, kosi bonsele lo. Olorire. Awa si fe kon di olorire. Ise apinfunni wa niyen. Awon tio le sorire gan tin l'aye lati sorire. Gbogbo le jerisi bi awon awon eyan lati ipo lasan l'aye ti bere sini sorire. Egbe imoye Krsna wa leleyi, afe ki gbogbo eyan sorire. Alasorire ni gbogbo eyan je, asiwere ni gbogbo awon eyan yi. Awa si fe kon sorire. Imoye Krsna niyen. Ti awon eyan ba je alaisorire ton je asiwere, kini iwulo pe eyin se iwaasu? Pe eyin jeki awon asiwere wanyi ati awon alaisorire wanyin di awon ton sorire iyen nitumi iwaasu. Iwaasu niyen. Sugbon afi teyin ba logbon tede sorire kosi besesle gba imoye Krsna yi. Oto oror niyen.