YO/Prabhupada 0321 - Always Connected with the Original Powerhouse



Lecture on SB 1.15.28 -- Los Angeles, December 6, 1973

Caitanya Mahāprabhu sowipe egbudo huwa to da, gege bon se so, āpani ācari, lehin na ele ko awo eyna imi. teyin o ba se bayi fun ara yin, kosi boro yin se fe lagbara. (isinmi) Evaṁ paramparā prāptam (BG 4.2). teyin ba ni asepo pelu ile-ina, ina ma wa lodo yin. Bibeko, waya lasan loma wa ninu ile yin. Kini iwulo re? Waya lasan o le ranyin lowo. Egbudo tibo ina. tio ba sina, ko wulo. Nitorina itunmo egbe imoye Krsna wa yi niwipe egbudo wa ninu ina olorun yi nigbogbo igba. Lehin na ibikibi teba lo, ina wa. Ina ma wa. Teyin ba yo ara yin kuro, Koni sina mo. gilobu ma wa, waya ma, gbogbo nkna ma wa Gege bi Arjuna sen ro niyen, " Arjuna nimi. Emi ni mo jagun ni ogun Kurursetra. Wan mo mi bi jagujagun to lagbara, ofa mi siwa. Sugbon nisin ko wulo mo. Miole ja mo, nitoripe, moti yora mi kuro pelu Krsna. Krsna ti lo. Nitorina osi bere sini ranti awon oro Krsna to ko lori ile-ogun Kurusetra.

Krsna o yato si awon oro to so. pipe loje. Nkan ti Krsna so ni odun egberun marun to koja, teba si gbo awon oror na, esi le ni asepo pelu re lesekese. Ilana to wa niyen. Seyin ri Arjuna evaṁ cintayato jiṣṇoḥ kṛṣṇa-pāda-saroruham. Nigbato bere sini ronu nipa Krsna ati awon oro to so lori ile-ogun, lesekese lo di santa. Lesekese l'okan re baale. Ilana to wa niyen. gbogbo wa lani asepo to daara pelu Krsna, kon se nkan eke. Nitorina tawa ba ni asepo pelu Krsna, koni si idanmu kankan mo. Alafia. Yaṁ labdhvā cāparaṁ lābhaṁ manyate nādhikaṁ tataḥ. Teyin ba ni ipo yi, ijeere to gaju niyen,ijeere to gaju , yaṁ labdhvā ca, lehin na nkan imi o le wunyin. Eyin na ma mowipe moni nkan to gaju. Yaṁ labdhvā cāparaṁ lābhaṁ manyate nādhikaṁ tataḥ, yasmin sthitaḥ. teba si wa ninu ipo bayi, lehin na guruṇāpi duḥkhena na (BG 6.20-23), awon idanmu to gaju gan o ni dayin laamu mo. Alaafia leleyi. Alaafia leleyi. KOn sepe nkna kekere, idanmu ti mu yin. teyin ba gbokan le imoye Krsna yi, idamu to gaju gan o le funyin ni ibanuje. Imoye Krsna to gaju leleyi. Ese pupo.