YO/Prabhupada 0324 - History Means to Understand the Activities of the First-class Man



Lecture on SB 6.1.20 -- Chicago, July 4, 1975

dharma-kṣetra ni Kurukṣetra yi je. Kon se nitori ogun ton ja nibe sugbon nitoripe Krsna wan'be lose di dharma-kṣetra. Nigbami awon ma se isotunmo bayi. suggbon o ti pe ti Kurukṣetra je dharma-kṣetra. Ninu awon veda wan sowipe, kuru-kṣetre dharmam ācaret: " Teyan ba fe see awon ebo keyan na lo si Kurusetra." eleyi sin sele ni orile-ede India, ti idanmu kankan ba wa laarin awon eyan meji, wan lo si ile-adura ni dharma-ksetra- kosi beyan sefe pa'ro niwaju orisa ton wan'be. Nkan to si sele gan tit disin niyen. Teyan gan ba ti je eni to paro gan, ton ba sofun pe " Nkan ton o, iro ni. So le tun so niwaju orisa na, " aye re ma ja, " rara." Orile-ede India leleyi. Kosi bosefe paaro niwanu awon orisa. Ese loje. Ema rowipe okuta lasaon ni orisa yi je. rara. Svayaṁ bhagavān. Gege bi Caitanya Mahaprabhu. Lesekese to ri irisi Jaganath, o si da ku. "Oh, Oluwa mi wa niwaju mi." Kon se bi awa: " Oh, sigidi lasan leleyi." Rara. Oro pe moriri. Be fe, be ko, Olorun fun ara re ni awon irisi yi je. oye ka ranti ni gbogbo igba Ka se jeje ka ma se niwaju awon orisa wanyi. Taban sise fun, tan fun l'ounje, tan wo so fun, agbudo ronu wipe, " Krsna fun ara re wan bi." Oun gan fun ara re ti sowipe, nitoripe awa o logbon lose le lati ni oye nipa re.

gege na agbudo tele gbogbo nkan to wa ninu sastra. Nkan ton pe ni iwa brahmana niyen. Itumo egbe imoye Krsna ni iwa awon bhramana. asa awon okurin lati ipo kini.. awon okurin pataki. Oye ka o wipe awon brahmana ni awon eyan pelu ipo kini ninu awujo awon eyan. Nitorina ni Krsna se sowipe, cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭaṁ guṇa-karma-vibhāgaśaḥ (BG 4.13). Itihāsa, itankole, itumo itankole ni lati ni oye nipa awon eyna kini. Itan akole niyen. Wansi mu awon eto to se pataki ju. Nitorina ni wan se fun wa ni apeere yi pe, udāharanti imam itihāsaṁ purātanam. Nitoripe, nkan pataki to sele niyen... bibeko, teba wo itan-akoole gbogbo agbaye ni asiko yi, talofe ka, talofe gbadun e, nibo lefe toju e si? Lojojumo ni awon nkan sele. Nitorina, awon nkan pataki nikan ni awon Veda ko sile. Nitorina lonse pe ni Purana. Itan akoole tayea atijo nitumo Purana. Purātanam. Nkan to ti darugbo gan nitumo Purātanam. Wanti ko wan sile. Gege na Śrīmad-Bhāgavatam yi je akojo awon eto itan akoole yi aye atijo. Itihāsa purāṇānāṁ sāraṁ sāraṁ samuddhṛtya. Nkan pataki nitumo Saram. Kon sepe ka kon ko gbogbo iran to sele. rara. Sāraṁ sāram, awon nkan pataki nikan, nkan ta ma kosile niyen. Nkan ton pe ni itan-akoole India niyen. Mahābhārata... India to lagbara ju nitumo Maha. Orisirisi nkan lo sele nibe, Sugbon awon to se pataki bi, ogun Kurusetra wanbe. Konsepe gbogbo awon ogun lon kosile.