YO/Prabhupada 0345 - Krishna is Sitting in Everyone's Heart



Lecture on SB 1.15.1 -- New York, November 29, 1973

gbogbo wa lani asepo pelu Krsna, Krsna si wa ninu okan gbobo wa. Krsna ni laanu wa gan, osin duru igba tama yipada si. Aanu re po gan. sugbon awon eda o logbon awa ti koju wa sibo mi lai wo Krsna. ipo wa niyen. Afe ki inu wa dun, pelu orisirisi nkan. Gbogbo eyan lon se nkan to wun, sugbon aon asiwere wanyi o mo, pe ilana to w alati ni idunnu ni Krsna. wan o mo. Na te viduḥ svārtha-gatiṁ hi viṣṇuṁ durāśayā ye bahir-artha-māninaḥ (SB 7.5.31). ni orile-ede yin orisirisi nkna lon dan wo, ile-giga to po, awon oko to po, awon ile nla nla, sugbon inu awon eyan o dun. nitoripe wan o mo nkan ton sonu. Nkan to sonu yi lawan fun awon eyan, " Egba Krsna, inu yin ma dun. Imoye Krsna wa niyen. Krsna ati awon eda ni asepo tinmo tinmo. gege bi Baba ati omo re, tabi ore s'ore, tabi Oga si Iranse,gege bayi awa sini asepo tinmo tinmo pelu re. sugbon nitoripe ati gbagbe ibasepeo wa pelu Krsna, tasi fe ki inu wa dun ninu ile-aye yi, nitorina lasen ni awon isoro wanyi. Ipo towa niyen. Kṛṣṇa bhuliya jīva bhoga vañcha kare.

Awon eda fe ni idunnu ninu ile-aye yi "Kilode tese wa ninu ile-aye yi, kilode teyin o se wa ninu ijoba orun?" ninu ijoba orun koseni toledi onigbadun, bhokata. Eledumare nikan, bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva... (BG 5.29). Kosi alebu kankan. awon eda na si wa, sugbon wan mo dada wipe Krsna nikan ni Oludari gbogbo nkan. Ijoba Orun niyen. Gege na ninu ile-aye yi oye ko ye wa pe, onigbadun koni wa, Krsna ni onigbadun, lehin na ijoba orun na loje. Egbe ioye Krsna yi fe jeki gbogbo awon eyan mo, wipe onigbadun koni wa, Krsna ni onigbadun na. Gege bi ara wa, ikun ni inigbadun, owo ati ese ati oju ati eti ati opolo wa, wan gbudo sise lati wa nkan tale gbadun kosi fi sinu ikun. Nkan iseda niyen. Gege na nkankana laje pelu Olorun, tabi Krsna, onigbadun ko ni wa.