YO/Prabhupada 0346 - Without Preaching, Without Understanding Philosophy, you Cannot Keep your Strength



Morning Walk -- December 12, 1973, Los Angeles

Umapati: Awa soro nipa basele fi awon elesin ninu ijoba lehin lo da waloju pe gbogbo nkan ti awon eyan fe laye isin, lawa o kin se. Awa feran inira fun Olorun. A feran Imoye Olorun. Awa o feran isekuse laarin okurin ati Obirin, awo kin moti. awon ofin meeerin wanyi je odi keji si nkan ti awon se nisin.

Prabhupada: Itumo re niwipe esu nigbogob awon eyan ni ilu-geesi wanyi.

Umapti: Gege na isoro to wani wipe bawo lase fe wonu ijoba, pelu gbogbo awon ofin wanyi, kade sofun wan , kon si dibo funwa.

Prabhupada: Awon eyan le ma dibo un yin, sugbn ema se iwaasu yin lo. Moti salaaye tele Awo eyan tio keeko po, se nitorin iyen agbudo ti awon ile-iwe giga? Ile-iwe giga gbudo wa n'be. awon eyan ton sorire wan losi be lati keeko. konsepe ka ma jiyan pe awon eyan o keeko nitoripe awon eyan o feran ile-iwe wanyi. Nitorina ejake ti awon ile-iwe giga wanyi." Kosejo.

Yaśomatīnandana: die die wan ma ni ifarasi.

Prabhupada: Beeni, Agbudo sise. Iwaasu niyen. Seyin rowipe, iwaasu rorun bayi. Ke jeun, ke sun nigbami ke korin " Haribol" Otan. Iwaasu koni yen. Agbudo mu imoye Krsna yi losi gbogbo agbaye.

Umapati: Lojo kan soso, ko leleyi ma sele.

Prabhupada: Adura si awon irisi Olorun loye ko toju wa. Teba fi sie, eyin na ma wo lule. ise wa o tan sibe. Arcāyām eva haraye pūjāṁ yaḥ śraddhayehate. Irisis Olorun nitumo Arcā. teyan ba s'adura si awon irisi Olorun, sugbon na tad-bhakteṣu cānyeṣu, tiko mo nkankan imi, taloje elesin, taloje ara ita, kini ise wa laayeyi, sa bhaktaḥ prākṛtaḥ smṛtaḥ, elesin ile-aye yi loje. Elesin ile-aye yi loje. agbudo gba aye yi lati fi mo eni ti elesin gidi je kini nkan ti ise wa je si awon eyan, lehin na ale ni ilosowaju. Lehin na ema di madhyama-adhikārī. Madhyama-adhikārī, elesin to ni ilosiwaju gege bi awon eyan ni orile-ede India ton kon losi ile-ijosin, wan si ile-ijosin lai mo nkankan. Nisin wa pa awon ile-ajosin yi de. Gege na tawa na o ba se dada lati sewaasu, awa na ma t ile-ajosin wa na. lai sewaasu, eyin o le ni ifarafun adura ninu ile-ajosin. laisi adura wanyi, kosi besele yasi mimo. awon nkan meji wanyi gbudo wa papo. Lasiko tawayi, awon Hindu, Musluman tabi Kristiani, nitoripe koseni to ko wan nipa imoye, nitorina lonse pa wanti, boya masalasi tabi ile-ajosin. Wan ma paati.

Prajapati: Awon eyan yi o le fi ise kankan han.

Prabhupada: Beeni. Iwaasu leleyi je. nitorina lasen ko gbogbo awon iwe wanyi. afi tawa na ba mu awon iwe yi, tase iwaasu, ta ka fun ra wa, tani oye nipa imoye na, egbe Hare Krsna yi na ma tan lehin odun die. nitoripe ko ni sina kankan, fun igba melo lema tesiwaju bayi, E korin " Hare Krsna" Haribol" eke niyen ma je. Kos'aye kankan ninu e.

Yaśomatīnandana: Otooro leso Prabhupada. Awa o logbon nitorina teyin o ba sofun wa bayi. Laisi iwaasu...

Prabhupada: laisi Iwaasu, lai ni oye nipa imoye na, kosi besele ni agbara kankan. gbogbo yi gbudo mo nipa imoye wa yi. Egbudo ka awon iwe yi lojojuo. Ie tani si po gan. Bhagavata si lagbara to he pe, eyikeyi ninu awon ese iwe teba ka, ema ri itunmo tuntun. O si da gan. Bhagavad-gītā tabi Bhāgavata. awon nkan lasan ko lonje.

Umapati: Moti gbiyanju lati fi awon Bhagavad-gia yin ninu awon ile-iwe, wan si sowipe, Awon imi " Ati ni Bhagavad -gita yi." Itunmo to yato gidi gan lori Bhagavad-gita leleyi," wan sowipe, " toba je nkan telomi tun ko, awa o fe gbo ipinnu elomi lori iwe kanna." Prabhupada: Ipo teyan ko leleyi, boseje lase so.

Umapati:O le nigbami lati...

Prabhupada: Iwaasu sooro nigbami. Moti sobee teletele. Nkan kekere koni iwaasu je. Ija ni Iwaasu je. Seyin ro pe, nkan kekere ni lati ja? Nkan kekere ko ni ija je> Ibikibi ti ija ba wa, alebu ma wa n'be Kinitumo iwaasu? Nitoripe awon eyan o logbon agbudo ko wan logbon. Iwassu niyen.

Nara-nārāyaṇa: Nigbateyin wa si ilu geesi wanyi, koseni to rope, egbe yi ma ni ilosiwaju sugbon oti ni ilosiwaju pelu iwaasu teyin se.

Prabhupada: Emi gan mio rope mole ni ilosiwaju bayi, kama wa soti awon elomi. Sugbon nitoripe mo sise bo seye, oti ni iklosiwaju nisin.

Yaśomatīnandana: Beeni, Aanu Krsna po gan to je pe, tawa ban reti nkan, asi fun wa ni nkan to po ju beee lo.

Prabhupada: Oh Beeni.

Yaśomatīnandana: Gege na tawa ba tele awon ilan yin, awon na mani ilosiwaju.

Nara-nārāyaṇa: tawa ba wa lori ipo to da, se awon ise oniselu wa leni ilosiwaju?

Prabhupada: Oh beeni. Krsna gan seto oniselu. gbogbo nkan niitumo imloye Krsna yi: awujo, onisleu, imoye, esin, asa, gbogbo nkan. Kon se nkan apa kan.Awon eyan o mo.Nitorin awa rope egbe esin lasann loje. Rara, gbogbo e wa ninu e, gbogbo e wa ninu re.