YO/Prabhupada 0351 - You Write Something; the Aim Should be Simply to Glorify the Supreme



Lecture on SB 1.5.9-11 -- New Vrindaban, June 6, 1969

Gege na iyasoto to wa laarin awon eye kuroo ati siwani niyen, gege na iyato to wa laarin awon eyan ton ni imoye Krsna ati awon eyan lasan. Awon eyan lasan wanyi dabi eye kuroo, awon eyan pelu imoye Krsna dabi eye Kuroo ati pepeye.

lehin na o sowipe

tad-vāg-visargo janatāgha-viplavo
yasmin prati-ślokam abaddhavaty api
nāmāny anantasya yaśo 'ṅkitāni yat
śṛṇvanti gāyanti gṛṇanti sādhavaḥ
(SB 1.5.11)

ele dabi ijuwe akosile, wansi ko dada,pelu awon amuye ijuwe akosile. sugbon kosejo pe wan yin Olorun logo. wanti salaaye pe odabi ibi ti awon eye kuroo tin gbadun. l'apa keji, ijuwe akosile imi tun wa, kini yen? Tad-vāg-visargo janatāgha-viplavo yasmin prati-ślokam abaddhavaty api (SB 1.5.11). awon ijuwe akosile ton fun awon eyan lati ka, sugbon to ni asise to po, sugbon nitoripe wan yin Olorun logo, o le da iyipada ninu gbogbo agbaye. O le so ile aye eda di mimo. Guru Maharaja mi ti sowipe, nigbaton wa awon iwe lati fi sinu " Harmonist", to ba ri wipe, olukowe na ti ko oruko " Krsna" tabi Oluwa Caitanya, a kan wo kiakia: " o da bayi, o dabayi ( erin). Odab bayi." O ti pe oruko Krsna ati Caitanaya, o da bayi.

Gege na taba tie ko iwe iroyin wa " Back to Godhead" tabi eyikeyi ninu awon iwe pelu ede tio da, kosejo kankan nitoripe awan yin Olorun Logo. Nkan ti Narada so niyen. Tad-vāg-visargo janatāgha-viplavaḥ. Janatā agha. awon ise elese nitumo Agha. teyan ba ka ila kan koba je pelu ede tio da, sugbon tiba gbo nipa Krsna, gbogbo awon ese re matan lesekese. Janatāgha viplavaḥ. Tad-vāg-visargo janatāgha-viplavo yasmin prati-ślokam abaddhavaty api nāmāny anantasya (SB 1.5.11). Alailopin nitunmo Ananta. Oruko re, ogo re, amuye re,wanti salaaye. Nāmāny anantasya yaśo 'ṅkitāni. Teba yin logo, kosi nkan to baje ti ede na o ba tie da, śṛṇvanti gāyanti gṛṇanti sādhavaḥ. gege ni Guru Maharaja mi, sadhu, awon eyan mimo, lesekese lo wa wo koja: Beeni. Oda bayi. Oda bayi. Nitoripe wanti yin Ol.orun logo. o daju pe koni ye awon eyan. sugbon nkan patai ni oun ti Narada so. teba ko nkan, lati fun Olorun logoo loye ko je. Lehin na nkan teko ma je pavitra, oyasi mimo. koba tie da gan, teba ko nkan ti o ni nkankan se pelu Olorun tabi Krsna, vāyasaṁ tīrtham niyen je. Ibi igbadun fun awon eye kuroo niyen.

Ipo Narada Muni niyen. Agbudo feti gbogbo kan wanyi. fun awon Vaisnava amure kan soso lowa: ni oriki. gbogbo yin gbudo mo oriki.. sugbon egbudo lo lati yin Olorun logo.