YO/Prabhupada 0358 - In this Life we Shall Make a Solution. No more. No more Coming Again



Lecture on BG 7.14 -- Hamburg, September 8, 1969

Nisin bawo lasefe pade iku? sebi ologbo ati aja? Kini iwulo ara eda? Awon ologbo ati aja, awon na si l'ara wan si pade iku. mosi lara temi, masi pade iku. Se oye kin pade iku bi aown ologbo ati aja? Iru eda eyan wo nimo je? rara. śāstra sowipe labdhvā su-durlabham idaṁ bahu-sambhavānte. lehin aimoye ibimo ninu ara orisirisi.. Ele ni oye nipa ilana itirana. Kon se bi ti Darwin, sugbon ilan itiranya yi wa nibe, awon Veda gan soro nipa re. lati ipo too kere ju si eyi to gaju ninu aye awon eranko. gege na agbudo ni oye nipaara eda eyan yi. Awa ti ri ara eda yi gba lehin aimoye aye atunwa ninu awon aye to kere juwa lo. Labdhvā su-durlabham. osi le gan lati ri gba. Eyin teje akeko oniye, ele mo ni aduro eda melo lowa. wan to 8,400,000 eda layeyi. ninu gbogbo awon eda eyan lo kere ju. Ninu 8,400,000 awon eda eyan je 400,000 ninu e; teba fiwe awon eranko o si kere. ninu eleyi awon eyan tio laju si po, wan da bi eranko gan gege na awon eyan bi iru tawa yi. ninu wan, wan o mo... opolopo ninu wan o moni eto emi mimo Manuṣyāṇām. Wanti salaaye ninu Bhagavad-gītā: manuṣyāṇāṁ sahasreṣu (BG 7.3). Ninu aimoye awon eda boya leyokan ma ni anfanni lati wa ona abayoo si awon isoro wa. gbogbo eyan ko. Opolopo awon eyan o mo nkan ti awon isoro yi je. wan o si fe mo. Wan rowipe " A dabayi, e jeki isor na wa. Ati wa saye yi, eja ka gbadun aye wa." Bi eranko lonje Sugbon ton sewaadi lati mo bonsele fi ipaari si awon isoro wan yi ni awon eda. eyan ko lawa iyoku je, eranko niwan. eti ri aye yi gba. Egbudo lo ara yi dada, lati fi paari isoro yi. taba kan gba ki awon omi okun iyika ninu ibimo ati iku, ma fun wa lara orisirisi, nkan tio da koniyen. Kosogbon kankan nibe. gege na egbudo lo ara yi lati waadi fun ona abayo si awon isoro aye yi. awujo Veda niyen. Wan man wa ona aboyo si awon isoro wanyi. Lati jeki awon isoro wa posi ati lati da awon imi sile ni bi ile aye yi se ri niyen. Awujo eyan to pipe ko niyen. awujo eyan t daju niwipe agbudo joko ka ronu dada, " Bawo nimo sele fi ipaari si isoro yi? Nibo ni mati ri imoye na gba?" Ara eda niyen. Bi awujo veda se ri niyen. Elo ara yi lati fi wa ona abayo si awonisoro wanyi. Ema kan ku danu, ki iku tode ewa ona abayo. E ma ku bi Ologbo ati aja. enikeni toba gbiyanju... awon Veda sowipe, etad viditvā yaḥ prayāti sa brāhmaṇaḥ: " Enikeni toba ku bonsen sise lati wa ona abayo, brahmana loje." enikeni toba ku bi ologbo ati aja, krpana loje. Itumo Krpana niwipe ko logbon lori. Kilode teyi se fe ku bi ologbo ati aja. Aghbudo ku bi brahmana. Teyin o ba ri ona abayo ninu aye yi, ema tun wa ni aye keji. gege b awon omo-okurin ton wa sodo wa, Oye ko ye wa pe ni aye wan to kehin, wan to gbiyanju na lati wa ona abayo si isori yi, sugbon wan opaari. Wan ti laaye imi Wanto salaaye awon nkan wanyi ninu Bhagavad-gita. gege na agbudo mu aye yi nipataki. awa eyan ton wa si imoye egbe Krsna yi. oye kan muise yi pataki, ni aye yi agbudo wa ona abayo. Awa o fe pada mo. Oye kan ni ipinnu bayi. gege nha imoye Krsna yi wa fun ipinnu yi, lati wa onaabayo si awon isoro aye yi kasi pada si ijoba orun, sibi tale ni imoye ayeraye. Ipinnu egbe imoye Krsna leleyi.