YO/Prabhupada 0362 - As We Have Got Twelve GBC's, Similarly Krishna Has Got GBC's



Lecture on SB 1.13.15 -- Geneva, June 4, 1974

teyin ban rin loju titi,, teba pa kokoro, ema jiya fun. ofin iseda leleyi. Ipo pelu alebo lto pa lawa. nigbogbo igba ni ijiya wa. nisin teba ni gbagbo ninu sastra kan imi niyen. teyin o ba ni gbagbo, ele se bo se wunyin. sugbon lati sastra ele ni pye nipa awon ofi iseda, tabi ke riwipw Olorun o gba iranu rara. gege na Maṇḍūka Muni si kilo fun Yamarāja, pe nigbati mo kere, laimo, mo se nkan tio yekin se, osi fi ya jemi bayi Nitorina wa di sudra, nitoripe ewo o le di brahmana tabi ksatriya. wansi sepe fun ko di sudra. Nitorina ni Yamaraja se wa bi Vidura ninu Oyun iya to je sudra. Itan akoole nipa ibimo Vidura niyen nigbato lo ikan ninu awon orisa Aryama sise re fun bi Yamaraja. Nitorina lonse sowipe abibhrad aryamā daṇḍam. ise gbudo lo, ipo adajo o le wa ni sisi. eyan gbudo wa sise na. Aryama losi sise na. Yathāvad agha-kāriṣu. Agha-kāriṣu. Itumo Agha-kāri... elese nitumo Agha ati Karisu. Eyan ton se nitumo Karisu gege boseye ko jiya nitumo Yathavat. Yathāvad agha-kāriṣu. Yāvad dadhāra śūdratvam. fun gbogbo igba ti Yamaraja je sudra, Aryama lon sise fun. ( O ka isotunmo) Vidura ton bi lati oyun iya toje sudra, wansi pase fun koma ba awon aburo okurin re Dhṛtarāṣṭra ati Pāṇḍu sere Bawo lose fe ni ipo oniwaasu lati le jise..? Idaaun to wa niwipe, gege boseje pe sudra loje lati ibimo, nitoripe o fi ile aye le fun imoye mimo labe idari Rsi Maitreya osi keeko gan labe re ninu awon eto imoye mimo, nitorina lonse fun ni ipo acarya yi, tabi oluko" Sudra ni Vidura je. Bawo lose ni oniwaasu?

Gege bi Śrī Caitanya Mahāprabhu, se so, enikeni to ba mo nipa imoye mimo Olorun yi, bobatie je ,brahmana, tabi sudra, tabi onile tabi sannyasi, ole di Oluko mimo." kon sepe nitori pe wa bi ni sudra kole sewaasu, kode le gba ipo acarya tabi Olouko mimi, Imoye Caitanya koni yen. imoye Caitany o ni nkankan see pelu ara wa, Imoye Caitanya ni asepo pelu emi wa. Egbe wa lati fun awon emi nni ilosiwaju. Nitorina nigbami oman ya awon eyan lenu awon nkan ara yi,iwa kanna loma je karma. lori ipo aye mimo, karma kanna loma je bhakti. karma kanna loma je bhakti. Sugbon bhakti o le wa lai se nkankan. Bhakt gbudo sise. Yat karoṣi yaj juhoṣi yad aśnāsi yat tapasyasi kuruṣva tad mad-arpaṇam (BG 9.27). bhakti yoga leleyi, nkan ti Krsna wi fun gbogbo eyan niyen, "teyi o ba le fi karma yin sile ko buru. Sugbon e funmi ni ijeere karma yin Lehin na adi bhakti."

Yamaraja ni Vidura je, Yamaraj lasan ko loje, ikan ninu awon olori loje awon olori mejila ton waninu sastra. Yamaraj je ikan ninu wan. Balir vaiyāsakir vayam. Nkan ti Śrīmad-Bhāgavatam so niyen. Ikan ninu awon GBC Krsna ni Yamaraja je. gege bi awa se ni GBC Mejila beena ni Krsna seni GBC Mejila

svayambhūr nāradaḥ śambhuḥ
kumāraḥ kapilo manuḥ
prahlādo janako bhīṣmo
balir vaiyāsakir vayam
(SB 6.3.20)

Awon eyan mejila ni idari lati sewaasu nipa imoye Krsna. agbudo tele wan. Mahājano yena gataḥ sa panthāḥ (CC Madhya 17.186). Nitorina lase da GBC yi sile. Wan gbudo je awon eyan ton daju. Bibeko wan ma jiya. Wanma di sudra GBC ni Yamaraj je sugbon o se asise ka, wansi fiyaje k di sudra gege na awon ton je GBC egudo sise dada lati jise ISKCON Bibeko wan ma jiya, Bi ipo na se gato gege na ni ijiya na se gato. isoro to wa niyen. Eyin na ti ri apeere Vidura Lesekese lon fiya je fun nkan kekere to se nitoripe awon rsis man sepe