YO/Prabhupada 0366 - All of You - Become Guru, but Don't Speak Nonsense



Lecture on SB 6.1.21 -- Honolulu, May 21, 1976

Oro to kehin ti Caitanya Mahāprabhu: kṛṣṇas tu bhagavān svayam (SB 1.3.28). Yāre dekha tāre kaha kṛṣṇa-upadeśa (CC Madhya 7.128). Caitanya Mahāprabhu, kini isọkiri egbe imoye Krsna yi? O sowipe " ki gbogbo yin di guru." Konsepe ke di guru eke, sugbon guru to daju. Nkan to fe niyen. Nitoripe awon eyan wa ninu okunkun, nitorina lase fe guru to po lati fun wa ni ominiran. Nitorina ise apinfunni ti Caitanya Mahāprabhu ni wipe " Gbogbo yin e di guru." Āmāra ājñāya guru haya tāra ei deśa. Konsepe egbudo lo si awon ilu ajeji. Ibikibi teba wa; e ko awon eyan l'eko; edi guru. Kosejo. Ei deśa. O sowipe, ei deśa. teyin ba l'agbara e le losi awon ilu ajeji, sugbon kon se dan dan. Ibikibi teba wa, ilu ki 'lu, e di guru. Ise apinfunni ti Caitanya Mahāprabhu leleyi. Āmāra ājñāya guru haya tāra ei deśa. " Ilu yi, nibi." Sugbon "mio ni amuye kankan. Bawo ni mosefe di guru?" Kosejo amuye. "Mosi le di guru?" Beeni. Bawo?" Yāre dekha tāre kaha kṛṣṇa-upadeśa: (CC Madhya 7.128) "Enikeni teba ba e soro nipa Krsna fun. Otan. E di guru niyen." Gbogbo eyan fe di guru sugbon awon asiwere wanyi o mo bonsele di guru, nkan to rorun ni. Awon guru orisirisi lati India ti wa si ilu yi, asiwere nigbogbo wan, nitoripe wan o fe so nkan ti Krsna ti salaaye. Boya egbe t'alakoko ton soro nipa imoye Krsna leleyi. Bibeko, nkan toyato ni awon asiwere wanyi n'ko awon eyan, kan ma sasaro, iyanje ni gbogbo e. guru to daju ma sofun yin nkan ti Krsna so. Konsepe a da awon eko re sile. rara. Caitanya Mahāprabhu niyen. Kosejo pe e fe da nkan sile. Ilan ti wan'be. E ni lati berre pe " bayi bayi" , otan. Se nkan to le niyen? baba ti sowipe, " gbohungbohun leleyi." Omode le sowipe " Baba sowipe gboh."ungbohun leleyi Oti di guru niyen. Kilo le nibe? Olori, baba re ti soro, " gbohungbohun leleyi." Omode le sowipe, " gbohungbohun leleyi." gege na Krsna ti sowipe " Emi ni Eledumare gbogbo aye." Tinba sowipe, " Krsna ni Eledumare gbogbo aye," kilo le nibe, afi tin ba fe yan awon eyan je lati di Krsna tabi Eledumare? Iyanje niyen. Sugbon tin ba so otooro pe, " Krsna ni Olorun gbogbo agbaye. Oun ni Oludari gbogbo nkan. Agbudo s'adura si," Kilo le nibe? Ise apinfunni wa niyen. Gbogbo yin ti wa sinu egbe imoye Krsna yi, ibeere wa niyen, ki gbogbo yin di guru, edi guru sugbon ema so isokuso. Ibeere to wa nkyen. E so nkan ti Krsna ba so. Leyin na eledi brahamana. Ele di guru, ati gbogbo nkan Ese pupo.