YO/Prabhupada 0407 - Life History of Haridasa is that He was Born in a Muhammadan Family



Discourse on Lord Caitanya Play Between Srila Prabhupada and Hayagriva -- April 5-6, 1967, San Francisco

Prabhupāda: Nigbayi brahmana kan wa ki Oluwa Caitanya "Moti fiwepe gbogbo awon sannyasi ni Benares, sugbon mo mope eyin o le ni nkankan se pelu awon Mayavadi Sannyasi, sugbon moti wa fiwepe yin na. Edakun e wa>" Beena Caitanya Mahāprabhu si ri aye ati pade Prakāśānanda Sarasvatī. Osi losi ipade na, wansi soro nipa Vedānta-sūtra pelu Prakāśānanda Sarasvatī, lehin na osi sodi Vaisnava. Nkan imi to sele leleyi.

Hayagriva: Iye odun melo l'okurin yi ni?

Prabhupada: Prakāśānanda Sarasvatī? Agbalagba ni. Ko kere ju ogota lo. Beeni.

Hayagriva: Kini ise ton se ni ilu na? Se Vedantist loje?

Prabhupada: Prakāśānanda Sarasvatī. Māyāvādī sannyāsī loje. O gba ilana ti Caitanya Mahaprabhu, osi teriba fun. O fowokan ese re. Osi parapo pelu re. Sugbon kosibi ton salaaye wipe odi Vaisnava, sugbon o gba imoye ti Caitanya Mahaprabhu. Sugbon Sārvabhauma Bhaṭṭācārya si di Vaisnava.

Hayagrīva: Apa Kaarun.

Prabhupada: Apa kaarun.

Hatagriva: Haridasa Thankura leleyi?

Prabhupāda: Haridāsa Ṭhākura.

Hayagrīva: Iku tale leleyi? Se iku Haridasa?

Prabhupada: Beeni. Arugbo ni Haridasa. Musluman loje.

Hayagirva: Oun llon ju sinu omi odo.

Prabhupada: Beeni

Hayagirva: Beena lehin gbogbo e na o ku, ninu apa kaarun.

Prabhupada: Iru nkan bayi o kan wa... Niotooro Haridasa Thakura si ni aye imi toyato, sugbon awa o le fihan.

Hayagriva: Beeni. O da. Nkan to sele yi.

Prabhupada: Nkan to sele yi se pataki, pe Caitanya Mahaprabhu je brahmana ati sannyasi. ni asa awon musulman koye ko fowokan enito je Muhammadan, sugbon Haridasa Thaura si je Muhammadan, nigbato ku osi gbe oku re tosi jo pelu re, lehin na osi sin oku re, osi pin prasadam. Ara Haridasa Thakura o ya fun bi ojo meji si meta. Nitoripe o je Muhammadan kole wonu ile ajosin Jagannatha. Nitoripe awon Hindu yi si le gan. Olufokansi loje, sugbon iru nkan bayi o dalebi. Kilode tose fe fa ijogbon? beena Caitanya Mahaprabhu si feran iwa pe kofe fa ijogbon... Nitoripe oti di olufokansi. ko losi ile-ajosin mo. Sugbon Caitanya Mahaprabhu asi wa lojojumo lati ri. Koto lo we ninu omi odo, a lo ri Haridasa. "Haridasa? Kilon se/" Haridasa a si teriba fun, asi joko fun gba die lati soro. Lehin na Caitanya Mahaprabhu asi lo we. Nijokan o si wa riwipe ara Haridasa o ya. "Haridasa? Bawo l'ara re?" Beeni Sa.. Kosejo, ara mi ni>" L'ojo keta o riwipe Haridasa ma ku. Beena Caitanya Mahaprabhu si bere lowo re, "Haridasa, kilo fe?" Osi ye awon mejeji. Haridasa sowipe " Asiko mi to keyin leleyi. Teba le duro siwaju mi." Beena Caitanya Mahaprabhu si duro siwaju re, lehin na osi ku. (isinmi)

Hayagriva: E ti salaaye pe...

Prabhupada: Lehin igba to ku, Caitanya Mahaprabhu fun ara re si gbe oku re, awon olufokansi to ku si mulo si eti odo lati sin oku na. Ibi ton sin si wa ni Jagannatha Puri. Haridāsa Ṭhākura samādhi, ibi ton sin. Beena Caitanya Mahaprabhu si bere sini jo. Idaray to sele niyen. Nitoripe ninu akoko idaray awon Vaisnava, kirtana ati ijo nigbogbo nkan. ayeye to kehin fun Haridasa Thakura niyen.

Hayagriva: E salaye wipe Caitanya jo pelu Haridasa?

Prabhupada: Oku Haridasa.

Hayagriva: Oh pelu oku re?

Prabhupada: beeni. Oku re.

Hayagriva: Lehin igba to ku.

Prabhupada: lehin igba to ku.

Hayagriva: Caitanya...

Prabhupada: Nigbati Haridasa si wa laaye, o jo. sugbin lehin iku Haridasa, Caitanya Mahaprabhu mu oku re o si bere sini jo ninu kirtana. Itumo re niwipe ayeye fun sisin oku Caitanya Mahaprabhu lose fun ara re. Osi mu oku na losi eti odo

Hayagriva: Oun lo se..

Prabhupada: Beeni: Ayeye si sin oku na, Beeni.

Hayagriva: Pelu kirtan.

Prabhupada: Pelu kirtan. Kirtan wa nigbogbo igba. lehin si sin oku na wan pin prasadam ati kirtana. Haridasa Thakura. Nibi egbodo fi awon oro pelu Haridasahan.

Hayagriva: Beeni. Se iroyin imi wa nipa Haridasa?

Prabhupada: Ile aye Haridasa ni wipe wa bi ninu ebi Muhammadan. Bakkan o di olufokansi osi bere sini korin fun igba 300,000 Hare Kṛṣṇa Hare Kṛṣṇa Kṛṣṇa Kṛṣṇa Hare Hare, Hare Rama Hare Rama Rama Rama Hare Hare, Caitanya Mahaprabhu si sod acarya, lori eto orin kiko. Nitorina lasen yin logo, "Nāmācārya Haridāsa Ṭhākura ki jaya." Nitoripe wan ti se ni acarya, lori eto orin kiko Hare Krsna. Nigbati Oluwa Caitanya gba sannyasa, Haridasa Thakura si fe wipe, " Oluwa mi, nisin etin kuro ni Nabadwip, kini mofe fi aye mi se? Emu mi lo tabi e je kin ku." Beena Caitanya Mahaprabhu sowipe, " Rara. Kilode tose fe ku? Tele me." Beena o mu lo si Jagannatha Puri. Ni Jagannatha Puri nitoripe won bu ninu ebi Muhammadan, ko wonu ibe. Beena Caitanya Mahaprabhu si fun ni ibi toma gbe ni ile Kasinatha Misra osin korin nibe, Caitanya Mahaprabhu asi fi prasadam ronse si. Bose gbe nibe niyen. Caitanya Mahaprabhu asi wa ki lojojumo, nijokan o si ku.