YO/Prabhupada 0420 - Don't Think That You Are Maidservant Of This World



Lecture & Initiation -- Seattle, October 20, 1968

Prabhupāda: (adura kiko fun ebo, awon olufokansi si daaun) Ese pupo. Nisin e funmi ni awon ileke, Ileke. Enikan... (Prabhupada s'aadura lori awon ileke, awon olufokansi korin japa) Kil'oruko re?

Bill: Bill.

Prabhupada: Oruko mimo re re ma je Vilāsa-vigraha. Vilāsa-vigraha. V-i-l-a-s v-i-g-r-a-h-a. Vilāsa-vigraha. Bere lati bi, ileke to tobi:

Hare Kṛṣṇa Hare Kṛṣṇa Kṛṣṇa Kṛṣṇa Hare Hare
Hare Rāma Hare Rāma Rāma Rāma Hare Hare

Ma jeki ika yi kan. Beena fun ikeji. bayi to ba de apa yi, wa tun bere lati ibi si apa keji. Awon olufokansin ma salaaye fun e. Awon aimase mewa si wa tawa ogbodo se. Ma salaaye fun e. So ni'we, awon aimase mewa?

Olufokansin:

Prabhupāda: Doobale. ( oro kan si keji pelu Vilāsa-vigraha ton tunso)

nama oṁ viṣṇu-pādāya kṛṣṇa-preṣṭhāya bhū-tale
śrīmate bhaktivedānta svāmin iti nāmine

Korin Hare Krsna inu re a si dun si. Ese pupo. Hare Krsna. (Awon Olufokansi korin japa) Kil'oruko re?

Rob: Rob.

Prabhupāda: Rob. Revatīnandana l'oruko mimo re. R-e-v-a-t-i, Revatī, nandana, n-a-n-d-a-n. Omo okurin ti Revatī nitumo Revatīnandana. Ikan ninu awon iyawo Vasudeva ni Revatī, iyawo baba Krsna. Balarama l'omo okurin re. Beena Balarama nitumo Revatinandana. Revatīnandana dāsa brahmacārī, l'oruko re. Korin lati bi, bayi bayi lo.

Hare Kṛṣṇa Hare Kṛṣṇa Kṛṣṇa Kṛṣṇa Hare Hare
Hare Rāma Hare Rāma Rāma Rāma Hare Hare

Lehin na ikeji. nayi wa de apa keji, lehin na tun bere lati'bi. Awon egbe re ma salaaye fun e. Doobale. Doobale. ( oro kan si keji pelu Revatīnandana ton tunso)

nama oṁ viṣṇu-pādāya kṛṣṇa-preṣṭhāya bhū-tale
śrīmate bhaktivedānta svāmin iti nāmine

Nisin mu ileke re ko bere sini korin. (Awon Olufokansin gbadura) Kilon fi se eleyi? Se irin loje? Kilode to wuwo bayi?

Okurin: Irugbin loje, Swamiji.

Prabhupada:Oh, Irugbin loje? Iru irugbon wo leleyi?

Okurin: Mio mo. Irugbin nla.

Prabhupada: O wuwo die. Bi ọta ibọn. ọta ibọn Krsna ( Erin) ( awon Olofokansi gbadura japa) Beena Śrīmatī dāsī l'oruko re. Śrīmatī. S-r-i-m-a-t-i. Śrīmatī dāsī. Rādhārāṇī nitumo Śrīmatī.

Śrīmatī: Kini itumo re?

Prabhupāda:Rādhārāṇī nitumo Śrīmatī. Itumo Rādhārāṇī dāsī niwipe oniranse Radharani loje. Ma rowipe oniranse loje si aye yi. ( Erin die die) Nkan oriire nla loje lato di iranse si Radharani. Beeni. Beena Śrīmatī dāsī, ni oruko re. Beena bere lati korin nibi,

Hare Kṛṣṇa Hare Kṛṣṇa Kṛṣṇa Kṛṣṇa Hare Hare
Hare Rāma Hare Rāma Rāma Rāma Hare Hare

Lehin na. E pada wa si apa keji ke tun bere. iyika merindinlogun. (oro kan si keji pelu Śrīmatī ton tun so)

nama oṁ viṣṇu-pādāya kṛṣṇa-preṣṭhāya bhū-tale
śrīmate bhaktivedānta svāmin iti nāmine

O da bee. Gba. Jeki inu re dun.

Śrīmatī: Hare Kṛṣṇa.

Prabhupada: Nibo ni iwe pelu asise mewa wanyi wa? Nibo ni iwe na wa? Ipo meta lowa lori eto orin kiko. Kini yen?

Okurin: Aworan to fowo ya.

Prabhupada: Oh, se wo lo yaa? O daa be. O da gan. Ese pupo.

Jāhnavā: pelu ibukun yin, se le fun Sharon? Sele fun Sharon pelu ibukun yin?

Okurin: Śrīmatī dāsī.

Prabhupāda: Ibukun loje.

Śrīmatī: Ese pupo.