YO/Prabhupada 0447 - Be Careful Not to Mix with Nondevotee who Imagines about God



Lecture on SB 7.9.2 -- Mayapur, February 12, 1977

beena taba wo iwa Lakṣmī-Nārāyaṇa, awa o le da awon ironu bi daridra-narayana mo tabi bayi bayi lo. Rara. awa o gbodo tele awon pasandi bayi.

yas tu nārāyaṇaṁ devaṁ
brahmārudrādi-daivataiḥ
samatvena vikṣeta
sa pāṣaṇḍi bhaved dhruvam
(CC Madhya 18.116)

Esu nitumo Pasandi, tabi alainigbagbo. Abhaktā hīna cara. Ema paaroo pelu awon alainigbagbo ton foriro nkan t'Olorun je. Won o ni gbagbo ninu eni t'Olorun je. Awon pasandi yi o mo nipa Olorun. Won rowipe kos'Olorun, sugbon wan sowipe, "Beena Olorun wa, sugbon kol'ori, ko lese, ko l'enu, koni nkankan." beena tani Olorun je nigbana? Awon oniranu wanyi sowipe nirakara. Itumo Nirākāra niwipe kos'Olorun. Wan sowipe k'solorun. Kilode teyin so bayi, " Beeni, Olorun wa, sugbon ko lori, ko lese, ko lowo"? Beena kilo wan'be? Itan je imi to wa niyen. Awon alainigbagbo wan sowipe, "Mio nigbagbo kankan ni Olorun. Kosi.." Eleyi si da. Sugbon awon oniranu wanyi, wan sowipe, " Olorun wa, sugbon nirākāra." Itumo Nirākāra niwipe kos'Olorun, sugbon nigbami oro ton lo ni nirākāra. sugbon itumo nirākāra yi niwipe Olorun o ni ākāra. Itumo ākāra yi ni wipe ākāra toni taye yi ko loje. Iśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇah-sac-cid-ānanda vigrahaḥ (Bs. 5.1). sac-cid-ānanda l'ara re je. Kosi besele ri iru eleyi ninu aye yi. sat ko l'ara wa; asat loje. Ara teyin ni tabi timoni, fun igba taye yi wa loma wa... Toba de ti tan, o paari niyen. Kosi besele tun ara yi ni. Nitorina asat.

Sugbon ara Krsna o ri bee. Nkanna ni ara Krsna je, sat; nkana loje . narakrti ni oruko imi fun Krsna. Ara ẹ̀dà aṣerẹ́gí lara wa je si Krsna, kon sepe ti Krsna lo jo t'awa. Rara. Krsna si lara, narakrti, nara-vapu. Awon nkan wanyi wa. Sugbon vapu ko jo asat. asat l'ara tani. kole duro. sac-cid-ananda l'ara to ni. asat l'ara wa ati nirananda - odi keji. Kole duro fun igba to pe, kode s'ogbo kankan, acit, kode si idunnu kankan. Ibanuje wa po gan. Beena itumo nirakara niwipe iru ara bi tawa ko. Ara re yato si tawa. Ānanda cinmāyā rasa pratibhavitabhis (Bs. 5.37). Ānanda-cinmāyā. Aṅgāni yasya sakalendriya vṛtti-manti paśyanti pānti kalayanti ciraṁ jaganti (Bs. 5.32). aṅgāni, aṅgāni, apa ara re, wanti salaaye, sakalendriya-vṛtti-manti. Mole ri pel'oju mi. Nkan tio oju wa fun niyen, lati le riran. sugbon Krsna: sakalendriya-vṛtti-manti - Lati riran nikan ko, sugbon o le jeun na p'eloju re. Sugbon awa o le ri, sugbon ounkoun taba fun Krsna toba ri, oti je na niyen. Aṅgāni yasya sakalendriya-vṛtti-manti. beena bawo lasefe fi ara Krsna fi we ara wa? sugbon avajānanti māṁ mūḍhāḥ (BG 9.11). Awon asiwere wan rowipe " Krsna lowo meji, ese meji; nitorina Krsna na lemi." Ema jeki awon asiwere wanyi tan yin je, pasandi. Emu oro ninu awon sastra, e keeko, ki inu yin ba le dun.

Ese pupo.

Olufokansi: Jaya Śrīla Prabhupāda!