YO/Prabhupada 0465 - Vaisnava Is Powerful, But Still He Is Very Meek And Humble



Lecture on SB 7.9.8 -- Mayapur, February 28, 1977

Beena Vaiṣṇava ni Prahlāda Mahārāja. Amuye awon Vaiṣṇava ni,

tṛṇād api sunīcena
taror api sahiṣṇunā
amāninā mānadena
kīrtanīyaḥ sadā hariḥ
(CC Adi 17.31)

Awon Vaisnava reesile gan - won se jeje wansi reesile. Vaisnava niyen. Awon Vaisnava lagbara gan, sugbon o reesile o sin se jeje. Aami to wa niyen. Prahlāda Mahārāja si wa pipe toje pe, lesekese ni Nrsimha-deva gbowo Re sori re: " Omo mi o ti jiya to. Nisin jek'okan re bale." Ipo Prahlada Maharaja niyen - lesekese ni Olorun gba s'odo. Sugbon o sin ronu, " Eyan lasan nimi, ton bi sinu ebi awon esu bayi, ugra-jateh. Koni igberaga pe " Nisin Nrsimha-deva ti gbowo re sori mi. Talo daabi emi? Emi ni mo gaju." Vaisanava ko niyen. Nigbati Sanātana Gosvāmī, lo ba Caitanya Mahāprabhu, O si farare han, nīca jāti nīca karma nīca saṅgī: " Won bimi sinu ebi awon eyan lasan, awon ise ti mon se na osi baramu, awon eyan timo sin paarapo pelu awon eyan tio da na." beena sinu ebi brahmana toda lon bi Sanātana Gosvāmī, sugbon nitoripe o bere sini sise fun oba Muhammadan, niotooro gbogbo iwa brahmana r si sonu. Konsepe won sonu, sugbon o babi wipe won sonu, nitoripe obere sini rin pelu awon Muhammadan, ton jeun pelu won, ton ba won joko, ton ba won soro. sugbon o si fi gbogbo e sile. Tyaktvā tūrṇam aśeṣa-maṇḍala-pati-śreṇīṁ sadā tuccha. O si bere lowo ara re, " KIni mon se? Ipara eni leleyi" Jāniyā śuniyā viṣa khāinu. Narottama dāsa Ṭhākura sowipe moti fun ara mi l'oro mu." teyan o ba mo to mu oro, ko buru, sugbon teyan ba laju to mu oro eyin s'aanu gan. Beena Narottama dāsa Ṭhākura sowipe,

hari hari biphale janama goṅāinu
manuṣya-janama pāiyā, rādhā-kṛṣṇa nā bhajiyā,
jāniyā śuniyā viṣa khāinu

Beena awa sin gbiyanju lati ti imoye Krsna yi lori gbogbo agbaye. sugbon, ti awon eyan o ba fe gba imoye Krsna yi, o dab'eni to laju ton mu oro. Ipo re leleyi. Oro lon mu. Otooror niyen. Kon sepe awa kon fori ro awon nkan wanyi, Won si mu wa lo si ile ejo, pe awa "po ori awon eyan". Beeni afe fo opolo na. gbogbo awon nkan idoti to wa ninu re, igbe asin gbiyanju lati fo fun won.

śṛṇvatāṁ sva-kathāḥ kṛṣṇaḥ
puṇya-śravaṇa-kīrtanaḥ
hṛdy antaḥ stho hy abhadrāṇi
vidhunoti suhṛt satām
(SB 1.2.17)

Vidhunoti, oro na wanbe. Fifo nitumo Vidhunoti. Fifo. Beyn sen gbo oro Śrīmad Bhāgavatam tabi Bhagavad-gītā, ilana to wa ni vidhunoti, fifo. Beena, fifo opolo loje -sugbon osi da. Fifo o kin se nkan to buru. (Erin) Awon asiwere wanyi o mo. Won rowipe, " Oh, efe s'omi bi mimo? Eyan buruku leyin je." Mūrkhāyopadeśo hi prakopāya na śāntaye: " Si awon asiwere, teba fun itosona, inu a bere sini bi." Mūrkhāyopadeśo hi prakopāya na śāntaye. Bawo loseje? Payaḥ-pānaṁ bhujaṅgānāṁ kevalaṁ viṣa-vardhanam.