YO/Prabhupada 0469 - Defeated or Victorious, Depend on Krishna. But Fighting Must Be There



Lecture on SB 7.9.9 -- Mayapur, March 1, 1977

Lori ise to daju lati bere egbe wa yi. Ebun eyikeyi tein ba ni, tabi agbara eyikeyi teba ni, tabi ikeeko eyikeyi teba ni... kosi nkankan toye ke ko. Ounkoun teyin ba ni ele lo lati fi sise fun Krsna. Konsepe eyin gbos keeko nipa awon nkan keto le sise. rara. Ninu ise na lema ko oun toye ke ko. Bese sise si, beena lema ni ilosiwaju teyin na ma di ianse to ni iriri. Awa o bere fun awon eyan ton logbon ju. Bibeko... Apeera to wa ni gaja-yūtha-pāya. Erin, ob awon erin, oni itelorun ara re. Eranko loje. brahmana ko leje. Vedantist ko loje. O si sanra na (erin) sugbon eranko loje. Eranko na ni Hanuman. Awon nkan bayi po gan. Eye ni jatayu. Bawo lonse ni itelorun? Jatayu lo ba Ravana ja. Laana eyin na ri. Ravana wa ji Sita devi gbe, eye Jatayu sin fo koja. Ravana na sin fo l'ofurufu lais'ero. Alagbara loje. Jatayu si peja fun lori afefe: Talo je? Iwo fe mu Sita lo. Wa ka ja." Beena Ravana si lagbara gan. Beena oun lo gba isegun na, sugbon Jatay ba ja. Ise to se niyen. Ema ronu wipe oun ko logba isegun na. Beena agbodo ja. Awon tan peja fun egbe imoye Krsna yi, agbodo ba won ja pelu gbogbo agbara wa. Ema je ko funyin ni ibanuje teyin o ba ni isegun. Ise wa na niyen. Krna ti ri ise na. Ijati tabi Isegun, e gbokan le Krsna. Sugbon agbodo ja. Karmaṇy evādhikāras te mā phaleṣu kadācana (BG 2.47). Itumo re niyen. Egbodo sise fun Krsna, pelu gbogbo okan yi, at'ogbon, ijati tabi isegun, ko wulo. gege bi Jatayu to ba Ravana ja. Ravana si ge apa re kuro, alagbara loje. Oluwa Ramacandra lo sin oku re nitoripe olufokansi loje. Ilana to wa niyen, kon sepe agbodo keeko si. Ounkoun ebun teba ni e lo lati fi sise fun Oluwa. Kosepe eyin gbodo je olowo, tabi ke lewa gan, tabi ke lagbara. Konse bayi. Sa vai puṁsāṁ paro dharmo yato bhaktir adhokṣaje ahaituky apratihatā (SB 1.2.6). Leyikeyi ipo teyin ba wa, ema jeki ise ifarasi Oluwa teyin se ko paari. Ofin toye ko wa niyen, pe awa o gbodo fi ipaari si ise wa. Krsna gan le gba idodo lasan, pel'omi die. Patraṁ puṣpaṁ phalaṁ toyaṁ (BG 9.26). Ko sowipe " E funmi ni awon ounje to lewa gan. Lehin na mole ni itelorun. Rara. bhakti ni nkan toye. Patraṁ puṣpaṁ phalaṁ toyaṁ yo me bhaktyā prayacchati. nkan to daju - bhaktyā. Bhaktyā mām abhijānāti yāvān yaś ca... (BG 18.55).

Nitorina awa gbodo ni bhakti, ife fun Krsna. Premā pumartho mahān, Caitanya Mahāprabhu ti fun wa ni itosona yi. Awon eyan sa tele dharma artha-kama mokṣa, sugbon Caitanya Mahaprabhu sowipe, " Rara, teyin ba tie nigbala, moksa, kole fun yin ni ore-ofe Krsna." Prema pumartho mahan. Pancama-puruṣartha. Awon eyan sin gbiyanju lati je elesin. O si da gan. won si fe eto aro aje. Dharma artha.Olowo nitumo Artha. lehin kama, igbadun iye ara dada. lehin mukti. Nkan t'awon eyna fe leleyi. Sugbon Bhagavata sowipe, "rara, awon nkan wanyi o le fun yin ni iranlowo kankan." Dharmaḥ projjhita-kaitavo 'tra (SB 1.1.2).