YO/Prabhupada 0472 - Don't Remain in this Darkness. Just Transfer Yourself to the Kingdom of Light



Lecture -- Seattle, October 7, 1968

Prabhupāda: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi.

Ajo: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi.

Prabhupāda:An s'adura si Govindam, orisun gbogob igbadun, Govinda, Krsna. ādi-puruṣaṁ loje, eda t'alakoko. Beena govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi. "Mo s'adura si" nitumo Bhajami. "Mo teriba fun mosi gba lati nife re." Awon oro to wa ninu adura ti Brahma leleyi. Iwe nla ni Brahma-saṁhitā yi je. ninu ese iwe karun, wanso wipe Oluwa, Govinda, O si ni isogbe re tonpe ni Goloka Vrndavana. O koja sanma ile aye yi. Sanma ile aye yi koja nkan teyin le foju ri, sugbon leyin sanmo ile aye yi ni sanmo mimo. Agbara ile aye yi ti bo sanma aye yi, mahat-tattva, idaboo meje lon bo ile, omi, ina, afefe. ju bayi lo, omi okun na wa, ju bayi lo ni sanma mimo yi ti bere. Ninu sanma mimi yi, ni isogbe to gaju wa ton pe ni Goloka Vrndavana. Wanti salaye awon nkan wanyi ninu awon iwe Veda, ninu Bhagavad-gita na. Iwe ti awon eyan mo gan ni Bhagavad-gita je. Wanti salaye nibe na,

na yatra bhāsayate sūryo
na śaśāṅko na pāvakaḥ
yad gatvā na nivartante
tad dhāma paramaṁ mama
(BG 15.6)

Ninu Bhagavad-gita wansalaye wipe sanma mimo imi wa, nibi ti kosidi fun orun Na yatra bhāsayate sūryo. Orun nitumo Sūrya ati bhāsayate itumo re ni ina orun. Beena kosidi fun ina orun. Na yatra bhāsayate sūryo na śaśāṅko. osupa nitumo Śaśāṅka. Kodesidi fun ina osupa. Na śaśāṅko na pāvakaḥ. Kosidi fun ina manamana. Ijoba ina loje. Nibi, ijoba okunkun ni ile aye yi je. Gbogbo wa la mo be. Okunkun nikan lo wa nibi. lesekese t'orun ban ran l'apa keji aye, okunkun tide. Itumo re ni wipe okunkun nikan lo wa nibi. Ina orun, osupa ati monamona lon fun n'ina Okunkun lowa nibi. Aimokan nitumo okunkun na. gege bi awon eyan se ni aimokan to po l'ale. Awa na ni aimokan yi, sugbon l'ale asi po si. Beena awon ilana Veda sowipe tamasi mā jyotir gama. Awon Veda sowipe, " Ema duro sinu okunkun. E bosinu ina." Bhagavad-gita na sowipe sanma kan wa t je mimo, atiwipe nibe na kosidi fun ina orun, tabi ina osupa, tabi ina monamona, ati yad gatvā na nivartante (BG 15.6) - Enikeni toba losi ijoba ina yi, kole pada wasinu okunkun aye yi. Beena bawo lasele losi ijiba ina yi? gbogbo iseda yi wa lori awon ofin wanyi. Awon Vedanta sowipe, athāto brahma jijñāsā. Atha ataḥ. "Nitorina egbodo sewaadi nipa Brahman, otito to gaju." "Nitorina nisin" itumo re niwipe... gbogbo oro na se pataki. Itumo " Nitorina" niwipe nitoripe eyin ti ni ara eda eyan yi - " Nitorina" itumo atah ni "leyinigbana." Eti koja aimoye aye nitumo " leyinigbana", eda aye 8,400,000. Eda omi - 900,000. Jalajā nava-lakṣāṇi sthāvarā lakṣa-viṁśati.