YO/Prabhupada 0477 - We Have not Manufactured a New Type of Religious Sect or Method of Philosophy



Lecture -- Seattle, October 7, 1968

beena egbe imoye Krsna yi, kole rara lati monipa re tabi lati se. Awa kan ni lati gbiyanju. Otan. Owo yin lowa, teba fe se, ele se. Nitoripe eyin si l'aye die lati gba nkan tabi lati fisile. aaye die teyin ni leleyi. tawa basi fi nkan to da sile, ibanuje ma mu wa lokan, taba si gba nkan to da, inu wa ma dunsi. Beena teba gba tabi teba fisile, owo yin lowa. Beena wan ti funwa ni imoye Krsna yi, awon olori pataki bi, Oluwa Krsna, Caitanya Mahaprabhu, iranse lasan lawa je. Awa kan fe pin kaakiri. Awa o da egbe tuntun kan sile. Rara. Nkan t'aye atijo leleyi, imoye Krsna. awa kan fe pin, bi awon eyan sele gba s'okan. Beena ibeere wa fun gbogbo awon eyan ton wa nibi tabi tio sinibi, pe ke gbiyanju lati ni oye nipa egbe imoye Krsna yi, tiko ba yeyin, e paarapo pelu wa, e biwa leere, egbiyanju lati mo. Awa osowipe ke tele bi afoju. E bi wa leere, egbiyanju lati mo, e ka iwe wa, lehin na omo ye yin. Kosi iyemeji nipa eto yi. teyin ba gba s'okan inu yin ma dun. gege bi ofin awon oselu. Afi ti gbogbo ipinle ba gba... gege bi orisi awon apa oselu to wa ni gbogbo ilu laye yi. Gbogbo won lon gbiyanju lati jeki egbe oselu won bosinu ijoba nitoripe kosi bi olori na sefe s'aseyori ti gbogbo orile-ede na o ba gba imoye re, ati apa oselu re. Sugbon Imoye Krsna yi si dara gan pe kosidi fun awon awujo tabi orile-ee tabi obi tabi egbe lati gba s'okan, ki inu yin ba le dun. Rara. Eyin, e gba fun ara yin. T'ebi yin o ba gba, t'awujo yin o ba gba, ti awon orile-ede yin o ba gba, kosi nkan to baje. Inu yin ma dun na. Sugbon t'ebi yin, ati awujo yn ati orile-ede yin ba gba, inu yin ma dunsi. Beena, nitoripe o wa pipe, beena enikeni toba gba imoye Krsna yi na inu re ma dunsi lesekese. Beena awa ti peyi. Asi ni awon ikeeko to po, pelu awon ile-ajosin orisirisi ni awon ile orisirisi, asi ni awon iwe., asi fe dayin loju pelu awon ikeko wa l'aaro ati ni irole. Beena ibeere mi wipe egbiyanju lati ni oye na. Caitanyer dayā kathā karaha vicāra. Keyin gbiyanju lati ni oye na. Ati fun yin ni imoye Krsna ke daajo si. teyin basi wo dada, te gbiyanju lati ni oye na, EYin na ma ri wipe, " Oh, osi da gan. Nkan pipe loje." Ibeere wa leleyi.

Ese pupo.