YO/Prabhupada 0480 - God Cannot be Impersonal, Because we are all Persons



Lecture -- Seattle, October 7, 1968

Awon eranko o mo ju kon gbadun. Won o lagbara kankan. Ogbon won o pe to . Gege bi adagun "Green park", awon pepeye po nibe. lesekese teyan ba wa pelu ounje die, gbogbo won ma pejo. " quack! quack! quack!". Otan. ton ba ti jeun tan, wan ni imo ako ati abo. Otan. Beena, awon ologbo at'aja ati awon eranko wanyi, ile aye eda ma ri bayi teyin o ba sewaadi lori ibeere " tani mi?" ti oun ton se pataki fun won ni iye ara won, kosiyato laari won ati awon pepeye at'aja. beena nitorina, ninu apa mefa t'alakoko iwe na wanti salaaye, pe oun mimo ni awon eda je. O si le gan lati sewaadi si ibi ti ina emi yi wa, nitoripe o ti kere ju. Kos'ero afiriran kankan tole sewaadi na. sugbon o wa n'be. Aami to fihan wipe o wa ninu ara mi ati teyin na, niwipe ele mi, ele soro, esi le ronu, Orisirisi nkan teyin se - nitori ina mimo yi. Beena ina kekere lati emi to gaju nigbogbo wa. Gege bi ina kekere se wa ninu ina orun. ti awon ina kekere wanyi ba paapo, ina orun niyen. sugbon awon ohun kekere lonje. Awon atomu kekere. Beena, ninu ibasepo pel'Oluwa at'awa na, oun kekere lati Oluwa laje, ton dan. Itumo didan yi niwipe asi ni awon amuye kankan pelu re, ironu, iye-ara, ife okan, ati gbogbo nkan bayi. Oun koun teba ri laara yi wa ninu Oluwa na. Beena Oluwa ko lese ko ma seyan, nitoripe eyan ni gbogbo wa. Moni iwa orisirisi - ni iwonba kekere. Awon iwa kankan wa ninu Krsna tab'Oluwa, sugbon ni iwonba tawa o le siro. Ikeeko nipa imoe Krsna leleyi. Ipo aye mi kere gan. Asi kere gan, sugbon ani ife okan to po, ise to po, irori opolo to po. Eyin na sele foju inu wo ke mo aduru ise , irori opolo, ife okan ati amuye t'Oluwa ni, nitoripe alagbara loje. Itumo agbara re niwipe gbogbo nkan teyin ni, gbogbo e lowa ninu e. Otan. sugbon nkankana laje, sugbon ni iwonba kekere. Alagbar aloje, asi kere si. Nitorina ìṣoníṣókí eto yi, gege b'ina kekere, tonba wa ninu ina, wan si dara lati wo. Sugbon tonba jade kuro ninu ina nla, won ma paare. Rara, kosina mo. Beena, ina kekere lati Krsna tab'Oluwa laje. taba ni asepo pel'Oluwa, lehin na ina yi a tun tan. Bibeko, ina yi ma ku. Botilejepe ina leyin je, ninu aye wa nisin, idaabo ile aye yi ti bo wa. Ina yi tife ku, apeere leleyi, kosibi ina ye sele ku. Toba ku, bawo lase fe wa laaye ninu ipo tawayi? Kole ku, sugbon wan ti bo mole. Gege bi ina ton bp, oru na ma jade sugbon eyin o le ri ina na pel'oju. Beena aso aye yi to bo ina mimo yi na, nitorina law o se leri. Dokita ti sowipe " Oh ara re o sise mo; nitorina okan re o sise mo. Oti ku." sugbon kilode ti okan na o sise mo, kole so. Kosi sayensi ologun kankan tole salaaye. Alaaye to po lo ma jade pe " awon oun pataki inu eje re ni o sise mo, wan ti di funfun, nitorina... Rara. Idaaun gidi ko leleyi. Eje wa ko lon fun wa l'emi. Awon nkan po gan laye yi ton pupa. Iyen o wipe won wa laaye.