YO/Prabhupada 0486 - In the Material World the Energy is Sex, and in the Spiritual World it is Love



Lecture -- Seattle, October 18, 1968

Alejo: Bawo lasele da yogamaya mo?

Prabhupada: ibeere tebere ko yemi.

Tamala Krsna: O fe mo basele da yogamaya mo, bawo lasele mo.

Prabhupada: Yogamya? Itumo Yogamaya ni oun ton so yin paapo. Iparapo nitumo Yoga. Nigbatryin ba bere sini ni ilosiwaju ninu imoye Krsna, ise yogamaya niyen. Teyin ba tin gbagbe Krsna, ise mahamaya niyen. Maya lon sise lori re. Ikan fa yin sile, ikeji sin tiyin si waju. Yogamaya. Beena, gege bi apeere na, pe eyin wa labe awon ofin ijoba. Kosi besele jiyan. teyin ba sowipe, " Mio fe tele awon ofin ijoba," kolese se. sugbon teyin ba je omo-odaran, eyin ma wa labe ofin awon olopa, Sugbon teyin ba je okurin jeje, ewa labe awon ofin ipinle. Awon ofin na wanbe. Ninu gbogbo nkan egbodo tele awon ofin ijoba na. Teyin ba se jeje bi olugbe to da, lehin na awon ofin ipinle ma fun yin ni idaabo. sugbon lesekese teyin ba si nkan ti ipinle na o fe, ofin fun awon odaran ma muyin. Beena awon ofin fun awon odaran ni mahamaya, isoro ona meta, nigbogbo'gba. Won wa ninu isoro kan nigbogbo'gba. apa ijoba Krsna fun awo eto wanyi, ānandāmbudhi-vardhanam. Eyin ma ni idunnu to po. ānandāmbudhi-vardhanam. iyato laarin yogamaya ati mahamaya niyen. Yogamāyā ... Yogamāyā, yogamāyā t'alakoko ni agbara Kṛṣṇa. Rādhārāṇī niyen je. mahāmāyā ita re, Durgā. Wanti salaaye nipa Durha yi ninu Brahma-samhita, sṛṣṭi-sthiti-pralaya-sādhana-śaktir ekā chāyeva yasya bhuvanāni bibharti durgā (Bs. 5.44). Orisa fun gbogbo agbaye yi ni Durga je. gbogbo nkan wa labe oludari re. Prakrti,agbara ni prakrti je. Abo ni agbara yi je. Gege awon eyan aye yi ton sise labe awon agbara kan. Agbara wo niyen? imo ako ati abo. Otan. Won ronu gan: " Oh lale yi mofe ni imo ako ati abo." Otan. Agbara to wa niyen. Yan maithunādi-gṛhamedhi-sukhaṁ hi tuccham (SB 7.9.45). Lori imo ako ati abo yi laye won wa. Otan. Gbogbo awon eyan sise dada, sugbon imo ako ati abo yi lo paari e. Otan. ile aye yi. Imo ako ati abo lagbara yi je. Beena agbara yi niyen. EYan ton sise ni ile-ero, teyin ba yo imo ako ati abo yi kuro, kole sise mo. Ti ko bale gbadun imo ako ati abgo yi, asi bere sini moti. Ile aye yi niyehn. Beena agbara yi gbodo wa. Ninu ile aye yi imo ako ati abo ni agbara to wa, ninu odo metalokan, ife l'agbara to wa. Nibi awon eyan ti ropo ife fun imo ako ati abo. Ife koniyen; ifekufe niyen. Pelu Krsna nikan nife yi wa, kosinibi kankan. Kosibi kankan tife yi wa. Iyipo ife low anibi. Ifekufe niyen je. Beena ife ati ifekufe. yogamaya nife je, mahamaya ni'fekufe. Otan. so ye yin?