YO/Prabhupada 0490 - Within the Womb of the Mother in an Airtight Condition for so Many Months



Lecture on BG 2.14 -- Germany, June 21, 1974

Ninu ese iwe kehin, wan salaaye wipe dehino 'smin yathā dehe kaumāraṁ yauvanaṁ jarā: (BG 2.13) "Awa n'paaro ara kan sikeji. Gege bi awa sen kuro lat'ara omo kekere si ara omode Beena, awa sin koja lat'ara kan si keji." Nisin, ibeere ibanuje ati idunnu loje. Ibanuje ati idunnu - gege bi ara tani. Okurin olowo ton gbe aye igbadun. Ibanuje yi si wa laarin opolopo awon eyan. Se wopo? Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi-duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9). Latini ibimo bi aja tabi oba, ibanuje yi nkankana loje. Kosi iyato kankan, nitoripe aja na sin wa ninu oyun iya re na, laisi afefe kankan fun osu to po, awon okurin, boya oba tabi enikeni, ogbodo ni isoro to po. Kosi ikewo kankan. Nitoripe eyin tini ibimo ninu ebi oba, iyen o wipe lati duru ninu oyun iya wa ibanuje na ma dinku, ati nitoripe oti ni ibimo ninu oyun aja, nitorina loseje alagbara. Rara. Nkankana loje. beena lasiko iku... lasiko iku ibanuje na po. Osi le gan toje pe eyan na ma farale. Gege bi igba ti ibanuje yi ti po ju, awon eyan man fiku parawon. Kole faramo: " e paari ara yi."

Beena koseni tofe f'ara yi sile, sugbon ibanuje yi lagbara tojepe eyan gbodo fi ara yi sile. Nkan ton pe n'iku niyen. Ninu Bhagavad-gita ele ri nibe, pe mṛtyuḥ sarva-haraś ca aham. Krsna sowipe " Iku nimi." kini itumo iku? Itumo iku niwipe " Moti gba gbogbo nkan lowo re. Otan. Moti gba ara re, Moti gba awon alabasepo re, moti gba orile-ede re, moti gba awujo re, moti gba ifowo iwontunwonsi ati gbogbo nkan ti tan." Sarva-haraḥ. Gbogbo nkan nitumo Sarva. Gbogbo awon eyan lofe ni owo topo ninu ifowo iwotunwosi ati ile to tobi, ati oko... Sugbon pelu iku gbogbo nkan ti tan. Beena ibanuje giga leleyi. Nigbami awon eyan man sukun. Ema riwipe lasiko iku, oju re ma jade kuro. Osin ronu wipe, "Moti se awon nkan to da latigbe dada, nisin gbogbo nkan ti sonu." Ibanuje nla loje. Moni ore kan ni Allahabad. Olowo loje. Beena odun merinleladota l'ojo ori re. Beena osin bere pel'ekun, lowa dokita, " Dokita, sele funmi ni odun merin si lati gbe ninu aye yi? Moni ilana kan ti mio ti paari." Kini dokita fese? " Kolese se, sa. Egbodo jade." Sugbon awon didinrin wanyi, won o mo. sugbon agbdo faramo. Agbodo faramo. Wanti funwa ni itosona, pe "nitoripe atini ara eda yi, egbodo faramo, lati gbe ninu oyun iya yin." Lehin na asi jade. Lehin na mio le soro. Kasowipe omode nimi, ati wipe kokoro n'ge mi je. Mio le sowipe " Iya" - nitoripe nigbayen mio le soro - " nkan ge mi je leyin." Mosin sukun ati iya mi rowipe " Ebi n'pa omode yi. Efun ni wara." (erin) Seri ri bayi.. Mofe nkan sugbon won funmi ni nkan mi. Otooro leleyi. Kilode ti omode yin sukun? Osi ni inira. Lehin na, bayi nimo se dagba. Lehin na mio fe losi ile-iwe. Sugbon pel'agid won mumi losi ile-iwe. Beeni. Boseje funmi niyen. (Erin) Mio feran lati losi ile-iwe. baba mi si dara gan. " Beena o dabe. Kilode tiwo ose fe losi ile iwe?" Masi sowipe, " Ma lo lola." " O da bee." Sugbon iya mi si se jeje. Boya tobajepe iya mi o si muna, boya mio tie ni keeko. Baba si se jeje gan. Beena iya mi man l'agidi. funmi. Oni okurin kan to man mumi losi ile-iwe. Niotoor awon omode o feran lati lasi ile-iwe, Wanfe sere. awon omode o fe losi ile-iwe, asi losi ile-iwe. idanwo na si wa, konsepe won losi ile-iwe nikan.