YO/Prabhupada 0492 - Buddha Philosophy is That you Dismantle this Body, Nirvana



Lecture on BG 2.14 -- Germany, June 21, 1974

Nisin kini ara eda yi? Ikojopo ohun aye yi l'ara eda je. Akojopo ile, omi, afefe, ina, ofurufu, okan, ogbon, igberaga - awon ohun mejo wanyi, marun je nkan tale foju ri ati meta t'awa o le foju ri Nkan ton fi da ara eda leleyi. Beena imoye Buddha niwipe egbodo wo ara yi sile, nirvana. gege bonse fi okuta ati igi fi ko ile yi. Beena teyin ba fo ile na, kos'okuto ati'gi mo. won ti pin sori ile. E ju sori ile. Lehin na koni si ile mo. Beena teyin o ba kin seyan, koni si ibanuje ati igbadun yi mo. Imoye won leleyi, imoye nirbana, sunyavadi: Efi ipaari si gbogbo nkan." sugbon kolese se. Kolese se. Eyin o le se. Nitoripe emi leyin je. A le salaaye. Eda tayeraye leyin je, Kosi besele se kema wa laaye. Ama salaaye nipa eto na, na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20), lehin igba taba fi ara yi sile agbodo gba ara imi, lesekese. lehin na nibo ni ibeere pe efe tu gbogbo ka? Pel'ona iseda eyin ma tun ara imi gba. Nitoripe eyin fe gbadun, lese wa sinu aye yi. Kosejo pe efe beere. Gbogbo ean mo wipe " Mo wa ninu aye yi. Mo gbodo gbadun dada." Eni tio mowipe " mo gbodo tun ara imi gba," ton rowipe, " Akojopo ile - omi , afefe ina leleyi. Beena toba ti wo lule, gbogbo e ti tan niyen. Beena bi mose wa laaye nisin e jekin gbadun dada." Nkan ton pe ni iwa awon eyan aye yi tabi t'alainigbagbo ninu Oluwa, ti mo wipe emi mimo laje, ara wa nikan l'an paaro. ninu ilu geesi awon alakowe giga, nkankana lon ro, pe ti ara eda ba tan gbogbo e lo tan niyen. Rara. Beeko. Nitorina ibere itosona leleyi. Dehino 'smin yathā dehe kaumāraṁ yauvanaṁ jarā (BG 2.13). Eyin kon paaro ara eda orisirisi. Eyin o le paari t'ara yin ba paari.