YO/Prabhupada 0501 - We Cannot be Anxiety-free Unless we Come to Krishna Consciousness



Lecture on BG 2.15 -- Hyderabad, November 21, 1972

kosi bi inu yin sefe dun. Awon omo okurin ati Obirin wanyi, lati America ati Europe, wanti se gbogbo nkan aye yi. Wanti se gbogbo tan Oko, ile-ijo, oti mimu, gbogbo eleyi lonti se. kosi'dunnu nibe. Nitorina lonse wa si imoye Krsna. nitorina, nāsato vidyate bhāvo nābhāvo vidyate sataḥ. Abhāvaḥ, ati sataḥ. nitori asat tagba ni ibanuje se mu wa Prahlāda Mahārāja ti salaaye: sadā samudvigna-dhiyām asad-grahāt (SB 7.5.5). Sadā samudvigna-dhiyām. awa o ni ifokan bale, isoro si po laaye wa. Oto-oro niyen. gbogbo lani isoro laaye wa. Kilode? Asad-grahāt. Nitoripe ati gba ara yi. Tat sādhu manye 'sura-varya dehināṁ sadā samudvigna-dhiyām. Dehinām. Itumo Dehinām ni wipe.... Deha ati dehī, ati salaaye gbogbo eleyi teletele. Olori-ara ni itumo Deha dehī ni gbogbo wa je, awon eyan tabi igi tabi eranko. gbogbo eda ni aye yi to l'ara, dehī ni gbogbo wan. gbogbo dehī towa ninu aye yi loni isoro nitoripe ati gba ara latinu aye yi.

kosi basele fi isoro segbekan afi taba gba imoye Krsna yi s'okan. Kolesese agbudo gba imoye Krsna yi sokan, brahma-bhūtaḥ prasannātmā (BG 18.54) - lesekese ni gbogbo isoro yin ma tan. teyin ba ko lati gba imoye Krsna yi, gbobo igba lema ni isoro. Sadā samudvigna-dhiyām asad-grahāt, hitvātma-pātaṁ gṛham andha-kūpaṁ, vanaṁ gato yad dharim āśrayeta (SB 7.5.5). Prahlāda Mahārāja ti fun wa ni ilana basele se, sadā samudvigna-dhiyām, then hitvātma-pātam, hitvātma-pātaṁ gṛham andha-kūpam... Gṛham andha-kūpam. Orisirisi itumo ni Gṛha ni. sugbon ni pataki ile ni itumo re Imoye Veda wa ni wipe agbudo kuro ni ile wa lati gba ipo sannyāsa, tabi vānaprastha. awa ogbudo jok s'ile titi digbati iku ba de, Ilana Veda koni yen lesekese tryan ba dagba,pañcāśordhvaṁ vanaṁ vrajet, ugbudo jade lati inu gṛham andha-kūpam. Gṛham andha-kūpam. inu wa lema dunsi taba soro nipa eto yi. sugbon agbudo soro lati inu sastra ituno gṛha. aṅganāśrayam ni oro imi fun Gṛha Aṅganā .Obirin ni itumo Aṅganā. Eyan ton gbe lbe iyawo re. Aṅganāśraya. sastra t salaaye wipe agbudo fi aṅganāśrayam yi sile, ka gba paramahaṁsa-āśrayam. lehin na lale ni igbala. Bibeko, gege bi Prahlāda Mahārāja se so gṛham andha-kūpam, " teba joko ninu bukata ile todabi konga, kosibi inu yin sefe dun si. Ātma-pātam. Itumo Ātma-pātam niwipe kosi besele ni oye nipa aye-mimo. sugbon nigbogbo igba ko. awaon eyan ti feran eto ile ati ebi wan ju... Aye ebi, aye awujo, aye Orile-ede, aye-agbaye. gṛham andha-kūpam ni gbogbo wan.gbogbo wan gṛham andha-kūpam lonje.