YO/Prabhupada 0504 - We Have to Study Srimad-Bhagavatam from all Angles of Vision



Lecture on SB 1.10.2 -- Mayapura, June 17, 1973

Krsna loda ile-aye yi sile, osi fe ka torju re dada. tloma toju e? awon alabasepo re. Awon esu ko. Nitorina loyeki awon Oba sise bi alabasepo Krsna latile seto aye yi dada. Awon Vaisanava mo bonsele lo ounkoun fun Krsna. Ipinnu fun ile-aye yi ni lati fun awon eda ni aye kansi lati ni igbala. Idi fun gbogbo re niyen. Ti gbogbo aye yi ba pare, gbogbo awon eda ma wonu ara Maha-Visnu lo. ti asiko iseda batunde, gbogbo awon eda na ma jade, gege bonse wole teletele. Awa osi gba iro ti Darwin so nipa awon eda tonwa lati ipo kekere... iru igbega bayi wa, sugbon gbogbo nkan loti wa ninu aye yi gbogbo awon eda toto 8,400,000, gbogbo wan lonwa. sugbon idayato siwa laarin wan. gege bi karma wan seri teletele karmaṇā daiva-netreṇa (SB 3.31.1), gbogbo eyan loma jade lati bere ise toye kose, pelu ara toye koni wa tunfun laaye kansi ati d'eyan kobale gbiyanju lati monipa ibasepo laarin oun ati Krsna, lati le nigbala. kosi pada sile... teba tun lo aye yi kilokulo - kosi besele kuro nibi, nitoripe nkan taye yi wa fun niyen. leekansi, taaye batun paare, ema tun pada sibi tewa teyin o le se nkankan. tobatun ya, etun jade. Sayensi nla leleyi. oyeki gbogbo awon eyan gbiyanju lati mo nipa ise awon eda . lehin taba ko awon eyan nipa ise yi ati oun toye kan se, agbudo ni Oba to daaju bi Maharaja Yudhisthira. Iranse Olorun ni Oba je. lehin igbaton pa awon esu yi tan, awon Kuru, kuror vaṁśa-davāgni-nirhṛtaṁ saṁrohayitvā bhava-bhāvano hariḥ niveśayitvā nija-rājya īśvaro yudhiṣṭhiram...

nigbato si riwipe Mahārāja Yudhiṣṭhira ti gba'joba lori ijoba aye," prīta-manā babhūva ha, Inure si dun si, " Alabasepo mi niyen, osi dami loju pe oma sise daada."

Nkan meji yi lon se. awon eyan ton fe gba'joba fun ara wan, wan ma pa wan danu. bakanna tabi keji wan pa wan danu. ikeji ni awon eyan ton fe gba'job alati toju re fun Krsna, Krsna asi fun wan ni'bukun, inu Krsna asi dun si. lasiko tawayi, ijoba onibo yi... koseni ton sise bi iranse Krsna. Esu gbogbo awon eyan yi. Esu ni gbogbo wan. bawo lesefe ki alaafia at'orire wa ninu awon ijoba bayi? kole sese. Teba fe.. agbudo ronu dada bi awon oni'selu,nitoripe nkankana laje pelu Krsna, Krsna sife ki gbogbo wan pada si ile, ni ijoba re. Awon Vaisnava gbudo riwipe awon eyan ni oye nipa imoye Krsna. taba lese kasi gba'joba lowo awon eyan yi orisirisi egbe lowa, egbe aon communist, egbe awon congress,.. egbe yi, tabi tooun Awa na gbudo ni egbe Krsna. sebeko? Inu awon eyan ma dunsi ti egbe Krsna ba gba ijoba. Lesekese ni alaafia ma wa. In orile-ede India ile-iperan to wa si po gan. maalu ton pa lojojumo to ẹgbàárùn, ni ilu toje pe nigbakan teni kan fe pa maalu, lesekese ni Mahārāja Parīkṣit se mu Obe re jade to fe pa onitoun, " tani e?" ninu Orile-ede kanna ni awon eyan tin pa maalu ẹgbàárùn, lojojumo, esi fe k'alaafia wa, k'orire wa? kole sese nitorina ti awon eyan tonje iranse Krsna ba gba'joba lesekese lonma fi'paari si ile-iperan, gbogbo awon ile-oti, ati hoteeli. lehin na lama ni alaafia at'orire. Bhūta-bhāvana, inu Krsna ma dunsi, " Iranse mi leleyi".

orisiri nkan lowa lati mo ninu Bhāgavatam gbogbo imoye ti awujo awon eyan bafe. agbudo mu oro yi ni pataki. Śrīmad-Bhāgavatam niyen.

Ese pupo.