YO/Prabhupada 0508 - Those who are Animal Killers, their Brain is Dull as Stone



Lecture on BG 2.18 -- London, August 24, 1973

gege bi ese-iwe kehin tati ka, avināśi tu tad viddhi yena sarvam idaṁ tatam. isiro emi ko leleyi, sugobn ele siro agabra re emi wa si kere tojepe kosi besele siro re. Kosi nkan telefi siro re, pelu oju lasan sugbon ele moni pa re lati imoye gege bigbati Caitanya Mahaprabhu daku ninu ile-Olorun Jagannatha Sarvabhauma Bhaṭṭācārya si riwipe kos'emi mo lara re kosi mi mo. teyan ba wa laaye to ba mi, ikun re na ma mi sugbon nigbati Sarvabhauma Bhaṭṭācārya fowokan ikun Caitanya Mahāprabhu ko mi rara. bayi na obere sini rowipe, dabiwipe sannyasi yi ti ku, sugbon osi fowo kan leyokan si osifi owu siwaju imu re nigbato ripe owu na mi die, inu re si dun gbogbo nkan loni isiro toyato sugon aprameyasya ni emi je iyen wipe kosi besele se isiro fun. Kosi Orisun fun. Nitorina awon onisayensi sowipe, kos'emi Rara, emi wa. aw si l'eri lati fihan. Ijerisi tawa ni niwipe ara wa ni imo-ohun. Ijerisi towa niyen Sugbon kosi besele se isiro fun. Wanti sofun wa pe imo-ohun yi wa ninu okan wa. Emi wa waninu okan wa. Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe 'rjuna tiṣṭhati (BG 18.61).

Emi wa ati Krsna na wa ninu Okan wa. Nitoripe won jo wapo, ale mo ibi ton wa. eyin na lemo lati imo-ohun ibi t'emi wa sugbon teba fe sewaadi kole sese. Nitorina lon senpe nu aprameya.Nkan tale foju ri nitumo Prameya Mole ri, mole fowo kan. Sugbon Krsna sowipe kolese se. Aprameya Bawo ni mosefe gba? Krsna sowipe Bawo ni mose fe gba nkan ti Krsna ba so? Krsna sowipe ukta, awon Olori ti p'ase si. Ukta. eto parampara. Krsna sowipe ukta Krsna o sowipe " Emi nimon soro" Ukta, ijerisi awon Veda. Nibo lowa? Ninu awon Upanisad.

bālāgra-śata-bhāgasya
śatadhā kalpitasya ca
bhāgo jīvaḥ sa vijñeyaḥ
sa cānantyāya kalpate

Owa ninu Upaniṣad, Śvetāśvatara Upaniṣad. Ijerisi Veda niyen. imi tun wa ninu Śrīmad-Bhāgavatam. kini yen? Keśāgra-śata-bhāgasya śatadhā, sadṛśaṁ jīvaḥ sūkṣma (CC Madhya 19.140). Sūkṣma, osi da gan. Jīvaḥ sūkṣma-svarūpo 'yaṁ saṅkhyātītaḥ kalpate. kosi besele siro awon jiva pe , ian, meji, meta, merin Asaṅkhya. Agbudo gba awon ijerisi lati awon iwe Veda Krsna na ti jeris pe kosibesele se isiro emi sugbon awa ni ijerisi nipa wiwa emi bawo lasele sowipe ko s'emi? Rara. Iranu niyen. Gbogbo agbaye ti wonu iranu yi. Nisin ni kan ko, teletele na. gege bi Cārvāka Muni, to je alainigbagbo. ko si da loju. Oluwa Buddha na si salaaye, sugon o tan awon awon eyan je. Kosi nkan tio mo nitoripe nkankanna loje pelu Olorun. Sugbon egbudo yan awon eyan je nitoripe awon eyan o logbon. kilode ti awon eyan yi o logbon?Nitoripe wan jeran, ogbon wan ti sonu. Keśava dhṛta-buddha-śarīra jaya jagadīśa hare. Opolo awon oni-peran babi okuta. kosi nkan tole wonu e. Nitorina agbudo fiipari si eran jije. taba fe ki opolo awon eyan si dagba dada, lati lemo nipa awon nkan to se pataki, wan gbudo fi eran jije sile.