YO/Prabhupada 0510 - The Modern Civilization, they have no Knowledge of the Soul



Lecture on BG 2.25 -- London, August 28, 1973

Pradyumna: Wan sowipe alaihan l'emi je, alainitumo, ati alainiiyipada. teba mo nipa eleyi kosejo pe eni ibanuje nitori ara yin".

Prabhupāda:

avyakto 'yam acintyo 'yam
avikāryo 'yam ucyate
tasmād evaṁ viditvainaṁ
nānuśocitum arhasi
(BG 2.25)

Krsna si ko Arjuna ni alakoko aśocyān anvaśocas tvaṁ prajñā-vādāṁś ca bhāṣase (BG 2.11). On soro bi alakowe sugbon on sukun fun ara eyan nkan tio ye ko se." Nānuśocanti. nkankanna lo wa nibi Tasmād evaṁ viditvainam, ara yi, na anuśocitum arhasi. Ma gbokan le ara yi Emi wa ni oro tose pataki. sugbon laye isin awa fe monipa ara wa. gbogbo nkan ti yi sodikeji Krsna sowipe nitoripe emi wa o le ni ipari, nitorian tasmād evaṁ viditvā agbudo ni oye ofin yi, enam, ara wa, na anuśocitum arhasi. Emi wa ni nkan to se pataki Sugbon agbudo fojuto emi wa, ara wa ko. Ibanuje ati idunnu ma wa ninu ara gege bi oju-ojo Āgamāpāyinaḥ anityāḥ, awon ibanuje ati idunnu wanyi fun igba die lon wa Tāṁs titikṣasva bhārata. Agbudo ko lati faramo gbogbo inira ati idunnu wanyi sugbon egbudo toju emi wa. Ninu awujo awon eyab nisin koseni tomo nipa emi, kamawa soro nipa bonsele toju e. gege ni awon eranko gbogbo wan lon seto ara wan sugbon iroyin emi, awon eyan o ni kamawa soro nipa titoju re. Iloseyin awujo wa leni niyen. Awujo eranko Awon eranko o moju ara wan lo nitoripe wan o mo nipa emi to wa ninu ara Awujo awon erank ni awujo yi, mudha. Eranko ni itumo Mudha, ketekete. sugbon awon eyan ma binu siwa ta ba sofun wa sugbon boseje niyen. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke (SB 10.84.13). moti salaaye ese-iwe yi teletele. Yasya ātma-buddhiḥ. Ara wa ni itumo Atma; buddhi wan ti mu ara eyan bi emi. Yasyātma-buddhiḥ. sugbon ara wo niyen? Apo tri-dhatu ni ara wa je, kapha, pitta, vāyu, ati awon ipase oja.. asepo ikunmu, ati ategun awon nkan wanyi.. gege bi ile-aye yi. Kini itumo ile yi? Tejo-vāri-mṛdāṁ vinimayaḥ. ounkooun toba wa ninu ile-aye yi, kini yen? Tejo-vāri-mṛdāṁ vinimayaḥ. ipaaro ina, omi ati ile. Tejo-vāri-mṛdāṁ vinimayaḥ. Paaro teba mu iyepe, ke mu omi ke yiwanpo, kefisinu ina, adi okuta ton le fi kole, toba je iyefun, adi simenti, teba tun kowon po ele ko ile-oke giga. ninu ile-aye yi ounkooun eba mu, ipaapo awon nkan meta wanyi lonje, pelu ategun ati ofurufu lati jekon gbe. Ategun leme fi je kon gbe. Akojopo awon nkan marun wanyi gege na akojopo nkan arun ni ara wa je. kosi'yato. sugbon nitoripe kos'emi ninu ile-giga nitorina lose wa loju kan, sugbon ara l'emi nitorina losele lo kakiri. iyato to wa niyen. Nkan pataki l'emi wa. sugbon awon eyan o mo. gege bi oko-afefe ton se, kos'emi ninu e sugbon eni ton wa daabi emi fun. Oun lon toju e, oun lon wa, nitorina lo sen fo. laisi emi, kosi basele rin kakiri. EMi gbudo wa ninu re bibeko emi toyato ma wonu re . Lehin na a bere sini rin Nitorina emi wa lose pataki, ara wa ko