YO/Prabhupada 0512 - Those who have Surrendered to the Material Nature, he has to Suffer



Lecture on BG 2.25 -- London, August 28, 1973

yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke
sva-dhīḥ kalatrādiṣu bhauma ijya-dhīḥ
yat-tīrtha-buddhiḥ salile na karhicij
janeṣv abhijñeṣu sa eva go-kharaḥ
(SB 10.84.13)

Go-kharaḥ. ketekete ati maalu ni itumo Go-kharaḥ.

kosi iroyin nipa emi ninu awujo awon eyan nisin awujo awon eranko lasan lonje, otan. Nitorina awon eyan yi o le ronu nipa ibajade iwa ton hu, awon eyan wanyi oni o le ronu nipa iwa orire. Ounkooun tonba ri lonma gba. Awujo awon esu. Pravṛttiṁ ca nivṛttiṁ ca na vidur āsura-janāḥ (BG 16.7). awon asiwere, tabi esu, alainigbagbo, ode itumo Āsura-jana niyen awon eyan wanyi o mo pravṛtti ati nivṛtti. Awon nkan toye ka se ni itumo pravṛtti awon nkan tio yeka se ni nivṛtti. nkan toje āsura-jana, awon eyan yi o mo. gege bi awa seni iwa toje pravrtti, loke vyavāya āmiṣa mada-sevā nityasya jantuḥ. gbogbo eda laye yi ni apa meji, apa mio ati t'aye yi. imo ako ati abo pelu eran jije ni iwa ile-aye yi eran, ati eja jije ni itumo āmiṣa, āmiṣa nirāmiṣa. ni awon eyan ton jeran. āmiṣa ati mada ati vyavāya. Imo ako ati abo ni itumo Vyavāya Loke vyavāya āmiṣa mada-sevā. imo ako ati abo, eran jije, ati oti mimu. Oti ni itumo Mada. Nityasya jantuḥ. Jantu. Enikeni toba wa ninu aye yi lon pe ni jantu. Eranko ni tumo jantu. Eda loje sugbon awa o le pe ni jiva. jantu lon pe iru eyan bayi. Jantur dehopapattaye. Jantu. Idagbasoke ara wa fun awon jantu, eranko. enikeni tio bani imoye, eranko tabi jantu loje. Nkan ti shastra so niyen. Jantur dehopapattaye. Talole ni ara yi? Jantu, eranko. taba tun ara gba nigbogbo igba , jantu tabi eranko laje. Kleśada āsa dehaḥ. awon eranko tabi jantu le farao nkan. gege bi awon ako-maalu ton sise lori oko tonsi na legba. Ogbudo faramo. Kosi bosele jade. gege a ton ba mu wan lo sinu ile-iperan lati pa wan, ogbudo faramo. Ko sono mi. Jantu niyen.

awon eyan tonti teriba fun agabra ile-aye yi, gbudo jiya. Ogbudo jiya. Kosona mi. Eti gba ara yi. Egbudo jiya. Kleśada āsa dehaḥ. Ijiya nitumo ara yi. sugbon awon eyan o mobe. wanse orisirisi eto lati ni idunnu, wansi fe ni alaafia laisi inira kankan, sugbon awon aswiere wanyi o mowipe, lesekese teyan bani ara yi, boya t'oba tabi ti kokoro - ogbudo jiya. Awon eyan o mobe. Nitorina ni Krsna se sowipe egbudo toju emi yin. Tasmād evam. Tasmād evaṁ viditvā. E gbiyanu ke ni oye nipa emi na. Kowulo teba beere sini sukun fun ara teni. Gbogbo e lonti to jo. Iwonba igbadun ati iwonba inira tema ni. sugbon ara wayi... Nitoripe lati amuye meta aye yi ni ara wa ti jade. Kāraṇaṁ guṇa-saṅgo 'sya sad-asad-janma-yoniṣu (BG 13.22).