YO/Prabhupada 0517 - Not that Because You are Born in a Rich Family, You'll be Immune from Diseases



Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

lati dauun si iru yoga bayi, ni Krsna se soro nibi: mayy āsakta-manāḥ. teba gbiyanju lati fokan si Krsna, to rewa gan... ton gbadun pelu Rādhārāṇī ati awon alabasepo re. mayy āsakta-manāḥ pārtha yogam, teba se yoga yi, mad-āśrayaḥ, yuñjan mad-āśrayaḥ. egbudo se yoga yi, lasiko kanna egbudo teriba fun Krsna. Mad-āśrayaḥ. Labe idaabo mi nitumo Āśrayaḥ teyin ba ni isoro laye yin, ele lo ba ore yin, " Oremi, iwo si l'agbaragan, eyan pataki ni e. Mosi wa lewu. Edakun mo teriba fun yin. edakun a gbami la.. ele se bayi fun Krsna na. ninu aye yi, teba fun enikan, enina le sowipe oun o le se, kooba je eyan pataki Ole sowipe, Mio le fun e ni'daaabo to fe". Idaaaun to wa niyen. teyin basini isoro to le gan teba loba ore yin , " Edakun se le ronmi low" enina le siyemji, nitoripe agbara toni kofibe po na. a koko ronu na, tin ba ran eniyi lowo, se koni di wahala funmi? Oma ronu bayi nitoripe, agbar are le a ka. sugbon Krsna si dara gan, osi lagbara gan, osi lowo gan.... Osi so ninu Bhagavad-gIta sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja: (BG 18.66) " efi gbogbo nkan sile ke teriba funmi" kini abajede ibe? Abakde na niwpe ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi: moma fun yin ni'gblal lati gbogbo ese teti se ninu aye yin".

gbogbo nkan tan se ninu aye yi kun fun ese. kosejo ise ati abajade. ounko teba se, ise na wa pelu abajede na. Bobatieje ise rere, abajade na si wanbe. gege bi awon Veda se sowipe, abajade ise wa .... Janmaīśvarya-śruta-śrībhiḥ (SB 1.8.26). kasowipe eyin o lese kankan l'aye yi, pe eyin je eyan mimo nigbogbo iwa teni. Eyin sin se ohun ofe, eyin si l'okan rere, gbogbo nkan si da fun yin. sugbon Bhagavad-gita sowipe karma-bandhana niyen. teyin base saara fun awon eyan, kasowipe e funwon l'owo, Eyin ma ri owo na gba l'ona merin, marun tabi mewa, ni aye atunwa. Oto oro niyen. Beena ninu imoye Vaisnava bi ese leleyi na seri. Kilode tose dabi ese? Eyin gbodo tun pada wa s'aye yi lati gba ijeere lori re. Iwa ese niyen. Kasowipe won bi yin sinu ebi awon olowo. Isoro pe ewa ninu oyun iya, nkankana loje. Boya eyin je eyan rere tabi elese, teyin ba wa ninu oyun iya.. awon isoro ati inira ninu oyun yin, nkankana loje, boya eyin dudu tabi e funfun, tabi olugbe India niyin tabi olugbe America tabi ologgbo tab'enikeni. Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi-duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9) awon isoro ibimo, awon isoro iku, awon isoro aisan awon isoro arugbo, nkankanna ibikibi teba lo. Konsepe nitoripe wan bi e sinu ebi to lowo, eyin o le ni aisan, rara beeko. Konsepe eyin o ni darugbo Konsepe ema jade kuro ninu awon isoro ibimo, tabi iku o le pa yin mo.

Oyeki awon nkan bayi ye wa dada. Sugbon awon eyan ologbon , wan o si fe mo.. Oh, Iku, oda. Iku. Eje kowa". Ibimo.. gege ni enu jometa wanyi, omode si wa ninu oyun iya re, orisirisi nkan to le fi ku pa si wa ninu be. Pupo. kilode? Nitoripe awon eyan tisomo awon nkna aye yi, to jepe kosi bonsele bimo na. ninu oyun iya re niwan ti pa. lehin na asi wole sinu oyun iya toyato, wantun fi ku pa. bayi kotie le foju ri oorun. Seti ri bayi lati wole sinu oyun iya, lati ku, tabi ka darugbo, tabi awon aisan tani, ise gidi koniyen. Teba je olowo, eyina gbudo jiya gbogbo awon isoro wanyi, teba si je talaka nkankanna loje.. kosiyato. Enikeni toba wole sinu ile-aye pelu ara eda, ogbudo gba gbogbo inira yi. Ele je omo-ilu America to je ilu to lowo ju iyen o wipe kos'aisan mo tabi awon eyan oni darugbo mo, kosi ibimo ati iku mo. eyan to logbon ni onitoun tole wa on abajade si aowon isor wanyi ologbon loje awon eyan ton fe lemo wansi fe wa onaabajade si awon isoro aye yi sugbon kolese se.