YO/Prabhupada 0522 - If you Chant Sincerely this Mantra, Everything will be Clear



Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

Prabhupāda: Beeni.

Viṣṇujana: Orisirisi iroyin lowa nipa Oluwa Caitanya bose so awon asiwere d'eyan gidi. wansi bere sini Korin Hare Krsna, tonba foju ri nikan. Bawo lasele gba ore-ofe yi lati je ki awon eyan na korin Hare Krsna?

Prabhupāda: teba korin mantra yi lt'okan yi gbogbo nkan loma bosi. eto gbigba idoti loje. teba ni awon asiwere teyin ni asepo pelu wan, iyen o se nkankan. ekorin nikan... gbogbo eyan lomo wipe ilana orin kiko yi nikan lole jeki awon eyan ni ilosiwaju. ilana towa niyen, Ekorin ke si gboran. efeti si awon iroyin latinu Bhagavad-gītā tabi Śrīmad-Bhāgavatam, egbiyanju lati ni oye nipa re, ekorin ke si tele awon ofin na Ekoko korin ke fetisi awon iwaasu na, lehin na ele bere sini tele awon ofin. Śṛṇvatāṁ sva-kathāḥ kṛṣṇaḥ puṇya-śravaṇa-kīrtanaḥ. Puṇya-śravaṇa-kīrtanaḥ (SB 1.2.17). enikeni toba gbo Hare Krsna, lesekese loma yasi mimo Toba ti yasi mimo, nigbato baya, agba imoye na s'okan. awon asi beere pe " kini gbogbo orin Hare Krsna teyin ko?" Se ti ri?" teba paaro fun wan pe kundalini yoga loje ati gbogbo iranu wanyi, inu wan asi dun.Seti ri? awon eyan yi feran enikeni tobale yan wan je. beena awon eyan tonle tan wann na mawa, "Beeni, egba mantra yi ke funmi ni dollar marundinlogoji, lehin osu mefa eyin na madi Olorun, ema ni owo merin" (Erin) Afe ki awon eyan tan wa je. Iyanje ni ikank ninu amuye ile-aye yi. awon alebu merin ile-aye yi siwa. Ikan ninu wan niwipe gbogbo lale s'asise. alebu imi to wa niwipe, ale gba fun gidi nkan tio ye ka gba. gege bi asise, iyen o le lati mo. gbogbo wa nibi lamo basen s'asise, awon eyan pataki gan man s'asise, seti ri bayi. gege bi awon oloselu, asise kekere tabi nla... iwa eda eyan ni lati s'asise gege na lasen gba fun gidi nkan tioye ka gba. bawo lose je? gege bi gbogbo eyan ninu aye ton rowipe "nkankan nimoje pelu ara mi". Sugbon moyato s'ara mi. Ara mi ko nimi itanra-eni, pramada leleyi. apeere to daaju ni taba rowipe ejo l'okun je. fun apeere tokunkun bawa, timo ba fowo kan okun mole sowipe " Oh, ewo ejo". Apeere to daju fun eto pe awan gba fun gidi nkan tioye ka gba. Alebu yi wa ninu aye gbogbo wa, sugbon asisie wa ninu iwa eda alebu keta niwipe afe tan awon eyan je, sugbon awon sile tan awa na je. Asi daju gan, gbogbo igba lan ronu basefe tan awon eyan je. beena ni onitooun ronu bosefe tanwa je. gbogbo ile-aye yi, abasepo laarin awon eyan ton yanje ati awon ton yan wa je. otan alebu imi niyen. Ikerin niwipe iye-ara wa ko fi be daju. Nitorina gbogbo imoye tati gba, gbogbo wan loni asise ninu wan Ale ni Okurin ton so sokuso, sugon lati okan re lonn se gbogbo eleyi, Otan. sugbon okan re o fibe daju. Nitorina kosi bosele so sokuso to, iranu ni gbogbo maje, otan. nitoripe Okan onitoun o daju. teba fe ele ko gbogbo awon odo papo koledi eyokan. Rara. Odo losije. Iranu ni gbogbo eto isokuso ti awon eyan fefi monipa Olorun. Nitorina pelu gbobo alebu ninu aye wa, kosi basele wasinu aye to da. Nitorina agbudo gba oro na lowo awon eyan gege bi Krsna ati awon alabasepo re. Imoye to daju leleyi. Lehin na ele ni ilosiwaju.