YO/Prabhupada 0524 - Arjuna is Eternal Friend of Krishna. He Cannot be in Delusion



Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

Prabhupāda: Beeni.

Jaya-gopāla: Ninu ese kerin iwe Bhagavad-gita wan sowipe Arjuna wanbe nigbaton salaaye oro Bhagavad-gita ni orisa-oorun ni aye atijo. talo je nigbana?

Prabhupada: Oun na si wanbe sugbon oti gbagbe.

Jaya-gopāla: kini ipo toni nigbana toba jepe ile ogunt Kurukṣetra ko lonti so?

Prabhupāda: Agbara Olorun lofi Arjuna sinu ipo yi... gege bi awon ile-isere , baba ati omode le sere paapo. Baba le sere bi Oba, omo na le sere bi Oba imi tio feran Oba t'alakoko. Sugbon ere nikan lonse. gege na, Ore ni Arjuna je si Krsna. Kosi bosel ni itanra eni. bawo losele ni itanra eni ti Krsna ba je Ore re? sugbon oye ko sebi wipe, ko mo nkan ton se, gege bi awon eda Krsna de salaaye gbogbo nkan fun. Osere bi awon eda lasan, nitorina gbogbo ibeere re dabi te awon eda ile-aye yi. Nitoripe awon akeko Gita ti sou teletele. Wanti salaaye. nitorina ni Krsna sefe tun eto yoga yi se pelu ilana Gita. Enikan gbudo bere. gege bi wo sen beere na, mosin daaun. gege Arjuna si rowipe koye ko wa ninu ipo eyan toni itanra-eni, osi so ara re di alabasepo awon eda ile-aye yi, osi beere orisirisi nkan, Olorun si daaun.