YO/Prabhupada 0537 - Krishna is Open to the Poorest Man for Being Worshiped



Janmastami Lord Sri Krsna's Appearance Day Lecture -- London, August 21, 1973

awon sastra sowipe, janasya moho 'yam ahaṁ mameti (SB 5.5.8). itanra-eni imoye "emi" ati "temi. maya nitumo gbogbo itara-eni wanyi. teba fe jade kuro ninu itara-eni yi, maya, egbudo gba itosona Krsna. Mām eva ye prapadyante māyām etāṁ taranti te. gbogbo nkan fun itosona lowa ninu Bhagavad-gita table gba imoye Bhagavad-gita boseje. gbogbo nka lowa nbe. Alafia wanb, owo wanbe. otooro niyen. Sugbon awa osi fe gba. orire wa tioda niyen. sugbon ale funi isotunmo mi tabe fe. Ninu Bhagavada-gita Krsna sowipe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). Krsna sowipe " E ronu mi, "man- " edi elesin mi. " Mad Yaji, " Egbadura si mi". Māṁ namaskuru, e teriba funmi." se nkan to lee gan niyen? Irisi Krsna leleyi. teba ronu nipa Radha-Krsna ninu awon irisi wanyi, se iyen na le? Man-mana. ke wa si ile-Olorun, gege bi awon elesin, ke teriba fun awon irisi towanbi, man-manā bhava mad-bhakto. kesi gbiyanju lati wsadura si irisi na, patraṁ puṣpaṁ phalaṁ toyaṁ yo me bhaktyā prayacchati (BG 9.26) konsepe Krsna fe gba gbogbo oun ini teni. talaka gan le sadura si Krsna. kilofe? Osowipe patraṁ puṣpaṁ phalaṁ toyaṁ yo me bhaktyā prayacchati: " pelu ifarafun, teyan ba funmi ni ewe kekere, ati eso kekere, at'omi die, mole gba. kon sepe ebi npa Krsna, sugbon osi fe ka di elesin re. koko oro niyen, Yo me bhaktyā prayacchati. ofin to se pataki niyen teba fun Krsna ni nkan kekere.. kon sepe ebi npa, Krsna sin fun gbogbo eyan lonje. Eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Sugbon ife yin ati ifarafun ni Krsna fe. nitorina losen bere lowo yin patraṁ puṣpaṁ phalaṁ toyaṁ. Man-manā bhava mad-bhakto. kosi isoro lati monipa Krsna tabi lati gba imoye Krsna yi sokan. Sugbon aw o ni se, aisan wa niyen. bibeko, ko le rara. lesekese tab di elesin Krsna ni gbogbo nkan ma yewa. iṣejọba ajumọlo nkankanna ni pelu imoye Bhagavata, nitoripe awa si gba Krsna bi baba to gaju, omode ni gbogbo wa jesi Krsna.

Krsna si sowipe oun ni Olori gbogbo planeti, sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29). nitorina ounkooun toba wa, boya l'ofurufu tabi ninu omi tabi n'ile, Krsna loni gbogbo e. nitoripe omode laje si Krsna, Nitorina ni gbogbo wa seni agbara lati lo oun-ini baba wa. sugbon ema gba nkan elomi. Itosoan fun alaafia niyen. Mā gṛdha kasya svidhanam, īśāvāsyam idaṁ sarvam (ISO 1). Olorun ni Olori gbogbo nkan. Omo Olorun niyin. eyin na lagbar ati lo oun-ini baba yin, sugbon ema mu ju boseye kemu. ele jiya fun. Wansi sobe ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Stena eva sa ucyate (BG 3.12), ninu Bhagavad-gita, ole loje". enikeni toba mu ju bose yeko mu, ole ni onitoun. Yajñārthāt karmaṇo 'nyatra loko 'yaṁ karma-bandhanaḥ (BG 3.9) Krsna ni itumo Yajna. Yajnesvara ni oruko imi ti Krsna ni. E sise fun Krsna, egba prasada. Nkan tawa ko awon eyan niyen. Ninu ile-Olrin yi tawan gbe awom omo ilu America, awon omo ilu geesi, awon omo-ilu Canada, awon eyan lati Africa, ati orisirisi ilu ninu agbaye yi seyin na mowipe, ninu ile-Olorun yi nikan ko, gbogbo agbaye. (isimi)

Onigbadun ati ore gbogbo wa ni Krsna je. tabt gbagbe eleyi, atun pada si ile-ae yi atun bere sini ja pelu ara wa. ile-ae yi niyen Awon oloselu, awon aforowero, awon alakowe, gbogbo wan lonti gbiyanju, sugbon kosi eyi toni ilosiwaju ninu gbogbo wan. gege bi apaapo-orile ede. ton daale lehin Ogun agbaye keji, wansi fe paari gbogbo ija pelu alaafia. sugbon ko si nkan to dabe. Wansi ja lo laarin Pakistan ati India, laarin Vietnam ati America lana toye kon gbakoniyen. Imoye Krsna ni ilana na. gbogbo wa gbudo mowipe, olori ko ni wa. Krsna ni Olori gbogbo nkan. oto-oro niyen. gege bi America. odun ogorunmeji tokojaawon ara-ile Europe si wasi America oni-ile ko lonje - elomi loni ile na. kon to wa, elomi loni ile na tabi ile- lasan loje. Krsna ni Olori gbogbo nkan. sugbon eyin sowipe, emi nimo ni ile na. Janasya moho 'yam ahaṁ mameti (SB 5.5.8). Maya niyen.