YO/Prabhupada 0551 - Our Students Have Got Better Engagement - Sweetballs



Lecture on BG 2.62-72 -- Los Angeles, December 19, 1968

Prabhupāda: Paraṁ dṛṣṭvā nivartate (BG 2.59). Param, teyin ba nii nkan to da egbod fi eyi tio da sile, egbodo fi awon nkan lasan sile. Bi iwa tani se ri niyen. Gege bi awon akekoo wa, Awon Akeko America, gbogbo won lon jeran teletele. sugbon nisin ikan ninu awon akeeko wa lonse adun nisin, adun IKSCON, wande ti gbagbe eran jije. Won o fe jerann mo. Won ti ni nkan to daju tonje, adun( Erin) Beena, boseje niyen. Teyin ba ni nkan to da lati se... Awa sin sa tele igbadun. Ānandamayo 'bhyāsāt (Vedānta-sūtra 1.1.12). Gbogbo awon eda lonwa igbadun. Iwa re niyen Kosi besele fi ipaari si. Gege bi omode ton wa igbadun, osi wo nkan sile. Oti wo nkan, sugbon inu re dunsi nkan toti wo mole. Beena awa o mo nkan ti igbadun je ninu aye yi. Awa sin wo lehin na atun ko. Ninu orile-ede yin moti ri ibi to po. Ile to da ton wo lule, nibomi ibi ton kole to da si. Se ri? Wiwo ati tunko. "Oh, ile yi ti darugbo. E wolule>" Iwa omode yi na, se ri bayi? Ilokulo asiko eda ninu ile aye yi. Wiwo ati tunko, wio ati tunko. " oko moto yi o da mo. ka tun ra imi." Awon eyan to po gan si ni iru moto yi. Seri bayi? Kini yen je? Looto, wiwo ati tunko yi dabi iwa omode. Setiri bayi? beena afi teyin ba ni ise to daju, imoye Krsna, eyin ma wa ninu ise wio ati tunko yi. Ise omode. Paraṁ dṛṣṭvā nivartate (BG 2.59). fun awon akeeko wa ninu imoye Krsna, Won wa bonsele ni wakati meji ju wakati merin le logun lo. Won ni ise to po gan.

Beena afi teyan ba nise ninu imoye Krsna, ogbodo sise fun maya, nkankana niyen. Awon eyan le soro dada nipa iru awon ise bayi pe, " Oh olowo lokurin yi je. Oti wo ile bayi sile osi ti ko ile to lewa gan." Beena, nkan to da gan leleyi loju awon eyan aye , sugbon ilokulo asiko won loje ninu eto mimo. ( korin) Hari hari biphale janama goṅāinu, orin yi. (korin) Manuṣya-janama pāiyā, rādhā-kṛṣṇa nā bhajiyā, jāniyā śuniyā biṣa khāinu. Peloju to la moti mu majele. majele. kIlode toseje majele? Ilokulo asiko wa ninu ara eda to niyi bayi dabi eni ton mu majele. Gege bi okurin ton mu majele, ko le mo nkan towa fun ninu aye to kan. Asi d'ewin. Fun awon odun to po, koni ni ara eda tale foju ri, ifiyaje re niyen. Seyin ti ri? Gaurasundara ti ko nipa eto ewin kan ninu iwe iroyin wa " Eyipada s'odo Metalokan. Ni ilu Geesi, ewin to ba Crowell ja? Osin ja titi deeni. Laale ema gbo ohun awon ton ja. Se ti ri bayi? beena itumo majele yi niwipe ile aye ara eda yi l'aye tani lati pada si imoye Krsna ati si odo metalokan. sugbon t'awa o ba sise ninu imoye Krsna, teyin kon sise wiwo ati tun ko yi, majele lawa n'mu niyen. Itumo re niwipe laye to kan ma wole sinu iyika ibimo ati iku yi ninu ara eda 8,400, 000, ile aye yi, beena ile aye mi ti baje. Awa o mo fun igba odun melo nimo gbodo se irin ajo yi, ninu iyika ibimi ati iku yi. Nitorina lose je majele.