YO/Prabhupada 0558 - Our Position is Marginal. At Any Moment, We Can Fall Down



Lecture on BG 2.62-72 -- Los Angeles, December 19, 1968

Prabhupāda: Beeni. tabi talakoko, Beeni.

Olufokansin: wan sowipe lesekese teyan ba losi odo metalokan, leyin igba taba pada si Krsna, pe awa o ni subu sinu aye yi. Sugbon won si sowipe latibe lati wa ni alakoko. Toba jepe ibe lati wa, bawo lase wa sibi?

Prabhupāda: Beeni. Gege bi apeere ti awon eyan pataki bi Brahma ati Siva, awon na le bosinu idanwo māyā. Beena, leyikeyi asiko a le jabo sinu aye yi, Nitoripe awa si je nkankanna pel'Oluwa ati nitoripe awa ninu ile aye yi, oye ko yewa pe ati subu. Sugbon eyin o le sewaadi lati mo bi eyin se bosinu ile aye yi. Sugbon ipo tawa ko daju. Leyikeyi asiko, ale wolule. Iwa yi wa n'be> Nitorina lon sen pe wa ni awon eda amugbalegbe. Gege boseje nkan to rorun lati ni oye nipa. Gbogbo wa lale ni aisan. Se beeko? Nisin teyin ba ni aisan, kowulo lati se waadi lati mo nigbati aisan yi ti bere. Eyin ni aisan l'aara, e gba iwosan yin, otan. Beena, awa ninu ipo ile aye yi. E gba awon iwosan yin, lesekese teyin ba ni iwosan, e se jeje kema tun wolule. sugbon aye imi wa pe, eyin le ni aisan laara na. Konsepe nitoripe eyin ti ni iwosan, kos'aye pe eyin fe ni aisan imi laara. aye imi wa. Nitorina agbodo se jeje gan. Beeni.

Olufokansi: Ninu Bhagavad-gita won salaaye lori oju iwe 41 pe Brahma ni oluko mimo keji. mo rowipe gbogbo awon oluko mimo won ma wa tayeraye, sugbon Brahma o le gbe tayeraye.

Prabhupāda: Beeni. Awa ma gbe tayeraye. ipaaro ara yi o kin se iku wa. Eyin ma wa tayeraye, Emi na ma wa tayeraye. Ipaaro ara eda yi nitumo Iku, otan. Gege bi eyin sen paaro aso yin, teyin ba paaro aso yin, konse pe eyin ti ku niyen. Beena ipaaro ara eda yi o kin sepe awa ti ku. tabi pe awa tini ara toyato kon sepe asese nibimo. kosi ibimo ati iku kankan fun awon eda laye yi, sugbon ipaaro ara eda yi n'sele nitoripe awa ninu ile aye yi. Nkan tonpe ni ibimo ati iku niyen. Looto kosi ibimo tabi iku kankan. Beeni?

Madhudviṣa: Prabhupāda, fun eni ton gbadura si Buddha se isogbe orun wa toma lo? Tabi se....

Prabhupāda: Hmm?

Madhudviṣa: Fun eni ton saadura si Oluwa Buddha,

Prabhupāda: Beeni?

Madhudviṣa: ninu bhakti-gaṇa(?), won sowipe teyan ba se ise fun Buddha, se isogbe orun wa tole le lati lo ba Buddha tabi.....

Prabhupāda: Beeni. Ipo to wa laari wa. Kon se isogbe orun. Ipo to wa laarin ile aye yi ati isogbe orun. Sugbon eyan gbodo pada wa s'aye yi. Afi teyan ba wole sinu sanmo mimo, kosi gba'aye ninu awon isogbe mimo... gege bi eyin sen fo lori ofurufu. Afi teyin ba lo si awon isogbe orun wanyi, eyin ma pada wa. Eyin o le fo lori sanmo nigbogbo'gba. Kolese se. Ipo towa laarin leleyi. Fifo yi o lese se ninu aye yi tabi imi. Fun igba melo leyin fe fo? Egbodo sinmi ide. Sugbon teyin o ba ni idaabo kankan ninu awon isogbe to gaju wanyi, egbodo pada wa. A le lo apeere kanna. Kasowipe eyin losi'ta sanma aye yi.. gege bi awon okurin ton lo nigbami. Awon man rowipe, " Oh oti lo jina gan, soke loke>" Sugbon koi ti lobi kankan. Asi pada wa. Atewo eke leleyi je, "Oh, oti losoke" Kinidi lati losoke? Eyin ma tun pada wa. Nitoripe eyin o lagbara lati wole sinu isogbe imi. Beena iranlowo wo ni awonero tegbe lo yi fe fun yin? Egbodo pada wa. Beena, eyin ma subu sinu omi okun Atlantic, tabi omi okun Pacific, lehin eni kan a lo mu yin. se ri bee? Ipo yin niyen. Beena lati fo ninu ofurufu pelu igberaga nitumo aisi Oluwa yi, " Moti wa soke giga bayi, moti wa soke giga bayo." (erin) Sugbon didinrin yi o mo fun igba melo loma wa lori ipo giga yi. Se ri bayi? asi sokale.