YO/Prabhupada 0566 - If the Leaders of the American People Come and Try to Understand this System



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Akoroyin: Se nkan ti Gandhi se leleyi?

Prabhupada: Huh? Se nkan ti Gandhi mo? Oniselu loje. Ko mo nkankan nipa asa yi.

Akoroyin: Mo kawipe nigbato pe odun 36 osi di akura,

Prabhupada: Looto oni awon ero nipa asa Hindu. Iyen da. Osi fi oro obirin sile, o da bee. Sugbon Gandhi o ni imoye to wa ni pipe> Seri bayi. Oniselu loje. Beeni, otan.

Akoroyin: Beeni. Okurin toni igboya gan. idaaun yi daju,..

Prabhupada: Nisin teyinba joowpo pelu wa, mole yi gbogbo nkna pada ninu ilu yi. Inu gbogbo won ma dun. Gbogbo nkan ma da. Egbe imoye Krsna yi da gan. teyin ma jowoopo. Koseni ton ranwa lowo. Afi awon omo okurn yi nikan, won ti wa lati ranmilowo. Beena egbe yi tin tesiwaju sugbon lona die die. Sugbon ti awon olori olugbe America yi le wa lati ni oye nipa kon si fi ilana wa yi ninu awujo yi, ilu yin loma daju ni gbogbo agbaye.

Akoroyin: Fun igba melo loti wa ninu eto yi?

Hayagriva: Odun meji at'aabo. Akoroyin: Odun meji at'abo? Omo odun melo ni e?

Hayagriava; Omo odun 28.

Akoroyin: 28 ni e. Nisin, se eleyi ti fiun yin ni iyipada?

Hayagriva: Ah, looto. (erin)

Akoroyin: Sugbon lati ona to daju, oro imo ako ati abo yi ti swami ti salaaye yi, bawo loti sise fun e? Seyin ti ri nkan too daju ninu e? Nitoripe funmi isoro nla loje si awon eyan ni asiko ewe won.

Hayagriva: Awon ife okan wanyi wa nibe, won si po gan. ife imo ako ati abo losi lagbaraju. Beena..

Prabhupada: Beeni, beeni.

Hayagriva: Beena awon ife okan yi ma yipada. Ama fi won fi sise fun Krsna.

Akoroyin: Oye mi, Oye mi, sugbon nkan ti mon bere ni wipe, son sise? so daju?

Hayagriva: Beeni, on sise. on sise. Sugbon egbodo koju si. Nigbami o le gan, nipataki ni beere, sugbon on sise. Egbodo koju si pe efe ko sise. Egbodo fe ko sise.

Akoroyin: Nisin, mofe ko yemi dada. L'ooro imi, Konsepe eyin rowipe eyin ti fi nkan sile.

Hayagriva: Rara, teyin ba ri nkan to daju...

Akoroyin: Nkan ti mon so niyen...

Prabhupada: Beeni. eyin tii gba nkan too daju.

Akoroyin: To daju. Beeni, konsepe eyin kan ge ete yin tabi ahon, "Mio ni fowokan, mio ni fowokan." Nkan imi wa alti ropo re.

Hayagriva: Eyin feran igbadun, eyin o le fi sile... Iwa eda niwipe awa o le fi nkan tani sile lai ni nkan to daju lati mu dani. Beena, egbodo ni nkan todaju nkan teyin fe fisile..

Prabhupada: Beeni.