YO/Prabhupada 0567 - I Want to Give this Culture to the World



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Akoroyin: fun igba melo leyin ti wa nibi Sa?

Prabhupada: Mowa sibi l' Oṣù Owewe 1965, lehin na ni Oṣù Ẹ̀bibi 1967 mosini ilera die, mo robe. Lehin na mosi pada losi India. Lehin na mo pada wa l'Oṣù Ọ̀pẹ̀ 1967, odun kan seyin Akoroyin; Beeni, mo ri bayi. Kilode tese wa sibi?

Prabhupada: Nitoripe mofe fun gbogo agbaye l'asa yi, osii yemi pe America ni orile-ede to ni ilosiwaju ju. Tonba gba, won le pin fun gbogbo agbaye. Ero mi niyen. Sugbon mosi ni ireti nisin, nitoripe awon omo alakowe Maerica wanyi, wanti mu egbe na nipataki Asin tewejada, won sin ko awon iwe dada. Beena arugbo nimi, mole ku, sugbon moti funwan l'ero yi. Asi tesiwaju bayi, won ma gba. Ati se idanwo na. Teba polowo re dada, lehin na awon eyan ma gba laisi kuna. Awon omo okurin yi ti wa ba mi, wan ti mu ni pataki. Beena mon reti.

Akoroyin: Moti ka iwe iroyin. Iwe iroyin to da niyen.

Prabhupada: Yipada s'Oluwa?

Akoroyin: Oh Beeni. Iwe iroyin to da gan.

Prabhupada: Ese pupo, Ese.

Akoroyin: O lewa gan. Nibo lontii se?

Prabhupada: Ni ilu New York.

Akoroyin: Ni New York nimoo ti ka eyi to kehin.. iwe iroyin to dara gan. Ah, awon melo lowa ninu egbe yi nisin?

Prabhupada: Moni die ju akeko ogorun ton tele gbogo awon ofin wa ni daju.

Akoroyin: Ogorun.

Prabhupada: Beeni. Ni orisirisi ile adura wa. Mosi ni ile adura bi metala. Awon imi sin sise ni London.

Akoroyin: Ni London?

Prabhupada: beeni, wan sise dada. Gbogbo won lonti feyawo. Emi nimo se igbeyawo fun won. Beeni. emi ni mo se igbeyawo na. Awon omo okurin, tio ju odun ogbon lo. Akeeko mi to dagbaju omo odun mejidinlogbon. Bibeko, 25, 24. To dagba ju 30. Ati beena awon obirin, e ti riwon na. Se ri. Beena mosin gbiyanju lati jeki inu won dun ni ile pko. Won o ni fe kankan si ile aye igberaga. won le gbe aye to rorun pelu awon nkan toye ka ni fu ara wa, sugbon pelu ironu to ga nipa imoye Krsna. Beena o damiloju pe tinba ku.. Nitoripe arugbo nimi, odun 73 nimi. Mole ku leyikeyi asiko. Sugbon nisin oda milojo=u pe egbe yi ma tesiwaju. Awon omo okurin wan yi mase. Ise apin funni temi niyen, bayi a le ni aseyori. Mowa sibi pelu ero ori yi, pe egbe imoye Krsna yi gbodo bere lati America. Nitoripe ounkoun to America ba gba, awon eya ma tele won... Looto Ilu Talaka ko ni America je. Beena o le yewon, won le gba sokan. awon omo-okurn lasiko ewe wan si ni idamu to po.