YO/Prabhupada 0569 - 'Swamiji, initiate me' I immediately say 'You have to follow these 4 principles'



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Hayagrīva: Conchshell.

Akoroyin: Mo rowipe shofar.

Prabhupada: Kini yen? Oniwako?

Akoroyin: iwo eran agbo.

Prabhupada: conchshell yi nkan mimo loje. Beeni. Looto ohun conchshell, beeni. Beena lehin igba tonba sadura s'Oluwa, asin fon fere.

Akoroyin: O dami loju pe moti bere gbogbo nkan toye kin bere. Kon se ibere tose pataki ju, sugbon mofe mo, nipa awon eyan bi Maharishi yi, ti mio tie fe gbo nipa re ati opolopo awon eyan. Omo-obirin mi si paarapo pelu nkan bayi fun asiko to po, sugbon won ti po lokan.

Prabhupada: Beeni. Nkan to wa niwipe awon eyan, awon eyan geesi, nipataki awon eyan lasiko ewe won, won wa nkan gidi, seri? Sugbon isoro to wa... gege bi emi. Teyan ba wa, " Swamiji e funmi ni itebomi." Lesekese ni masowipe " Egbodo tele awon ofin merin wanyi," wansi salo. Sugbon Maharishi yi, kofii aimase kankan, seri bayi? gege bi ologun, toba sowipe " Ele se ounkoun teba fe. E kan mu ogun yi, ara yin ma ya." Awon eyan ma feran iru ologun yi gan. Seri bayi?

Akoroyin: Beeni. Asi pa awon eyan to po gan, sugbon awon eyan ma feran e gan.

Prabhupada: Beeni ( erin) sugbon ologun toba sowipe " Oh, e ma se bayi, e mase bayi, ema je tibi", inira loje. Beena won fe nkan gidi. Otooro niyen. Sugbon lasiko kanna wonfe lofe. Nitorina awon eyan ma wa lati tan won je. Won gba aye na. " Awon eyan yi fe ka tan won je. Eje ka tanwanje." Se ri bayi. Bibeko,, won sofun awon eyan pe " Oluwa leyin, Oluwa nigbogbo wa. Eyin gbodo ranti, eti gbagbe. E gba mantra yi, eyin ma d'Oluwa, e ma lagbara. Ounkoun teba fe lele ni idari lori. kode si idari lori iye ara won. Ele moti teba fe, e lese imo ako ati abo ati ounkoun teba fe." Awon eyan bayi, "Oh sasaro fun iseju meedogun, mole d'Olorun, masi son dollar marunlelogoji lasan." Awon eyan to po gan ma wa, " Ni ilu yin dollar marunlelogoji konse.. sugbon teba pin marunlelogoji lona millionu ka, seri pe oti po si (erin) Awa sin sukun nibi nitoripe awa o le tan awon eyan je. Asin sowipe teyin bafe, egbodo tele awon ofin wanyi. Awa o le gba e ofin sowipe " Ema fiku pa," kin sowipe, " Beeni ele fiku pa. Awon eranko yi o l'eemi kankan." Awa o le s'aako bayi. Seri.

Akoroyin: O da nkan timofe mo niyen. Itiju loje nitoripe awon nkan bayi ti jeki opolopo ninu awon eyan lasiko ewe won fe gbo nipa re mo, awon eyan tio feran nkan bayi mo..

Prabhupada: Beena e gbiyanju lati ranwalowo. Egbe yi daa gan. Asi fun awujo eda ni iranlowo. Afun rile-ede yin ni iranlowo. Egbe to daju leleyi, awa o s'ako, kosi iyanje kankan. O daju. Beena mosin bere nitoripe...

Akoroyin: Talo jeerisi?

Prabhupada: Krsna lo jeerisi.

Akoroyin: Se awon osofin wa ton fun awon eyan ni iwe-ase lati sewaasu tabi ... Bawo lese fe so nibi?

Prabhupada: Kosin'be nitoripe ni India awon ile-ajosin yi po gan, awon eyan mimo ni awon eyan yi je. Beena teyin ba di akeeko eyan mimo, iyen je iwe-ase to daju. Gege bi orile-ede yin, awon eyan ni iwe-eri funigbeyawo. Ni India kosi iwe-eri kankan> Omo-okunrin ati obirin ma joko, niwaju awon obi won ati alufaa ati awon agba. Nkan ti mon se niyen. Kosi iwe-eri kankan. Sugbon fun gbogbo aye won ni ipaarapo yi ma wa. Kini iwe-eri fe se? Ayeye na si da tojepe, iyawo a sowipe " Oko mi leleyi tayeraye" oko na asi mu iyawo re " Aya mi leleyi tayeraye," Kosi bonsele tuka. Kosi itan akoole kankan ni India pe won funwon ni iwe-eri. Rara. Sugbon won si wa paapo, fun aye yi. Nisin, wonti bere sini ko iwa geesi, nipataki, ema binu awon olori wa ton ko asa geesi wonti bere lati mu awon nkan bi iwe-eri fun igbeyawo. Sugbon teletele awon nkan wanyi o sin'be.