YO/Prabhupada 0571 - One Should Not Remain in Family Life. That is Vedic Culture



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Akoroyin: Nisin.. seyin man losi egbe yi fun igba die?

Prabhupada: Kosi asiko towa tale lo sibe. Rara Sugon, baba mi lo komi leeko nipa eto yi.....

Akoroyin: Oh baba yin..

Prabhupada: Oh, beeni. Baba mi lo komi lati igb a timo kere. mosi pade oluko mimo mi ni odun 1922, mode gba itebomi... Lori gbogbo e, ibere mi daju, iwonba eyan tokoja idaji lonni imoye Krsna yi latinu ebi tonti wa. Seri bayi? Beena won ti kowa leeko lati ibere aye. ni daju, mo gba oluko mimo ni odun 1933. latigbana, moti ni agbetele tele lori eto na, nigbati mode ba oluko mi mosi tesiwaju lori eto na.

Akoroyin: Mori be, mori be. Beena eyin tin pin oro yi lati odun 1933.

Prabhupada: Rara. Motin pin lati odun... lati odun '59. Akoroyin'59, Mori bee. Kileyin se latigba yen...

Prabhupada: Onile nimi tele. Mon sise ni ile ogun. Teletele, alakoso nimi ninu ile-ise kemika. sugbon mo sin ko nipa imoyi yi botileljepe mosi je onile. Mosin te iwe Iyipada si odo metalokan...

Akoroyin: Beena lati gbayen leyin tin teweyi jade...

Prabhupada: ni India.

Akorin: Mori bee.

Prabhupada: Beeni, mo bere ni odun 1947 pelu ase oluko mimo mi. Beena, ounkoun timon pa bi owo ni mo na. Beeni. Mio jeere kankan sugobn mosin pin. Beena oti pe ti mo tin se ise yi. Sugbon leyin igba ti mo fi ehi mi sile, mosin sise na lati odun 1959.

Akoroyin: Seyin ni awon omode?

Prabhupada: Oh beeni, moni awon omo-okurin tonti dagba.

Akoroyin: E fi won sile?

Prabhupada: Beeni. Moni iyawo mi, awon omo -omo mi, gbogbo won, sugbon mi o ni nkankan se pelu won mo. Won se nkan tiwon. Iyawo mi wa pelu awon omo-okurin mi toti dagba. Beeni.

Akoroyin: O dabee...? Iru nkan bayi lee lati ni oye re na, lati fi ebi yin sile ati wipe e kan sowipe, " O daboo."

Prabhupada: Beeni, beeni, ase Veda niyen. Gbogbo awon eyan ni lati fi ebi won sile leyin odun 50. Eyan o gbodo joko sinu ile ebi. Asa Veda leleyi. Konsepe keyin ku, sinu ile yin. rara. eleyi o da.

Akoroyin: Seyin le salaye nipa eto yi.

Prabhupada: ni alakoko, awon omo-okurin gbodo keeko lati di brahmacar, ninu aye mimo. Lehin na wan fun ni itosona pe ko feyawo. toba le fun lati ni idari lori iwa imo ako ati abo re, wan si gba laye. " O dabee. Wa iyawo kosi fe." Lehin na asi wa ninu ile ebi yi. Beena ni odun 24 tabi 25 asi se igbeyawo. 0dun 25, e je ko gbadun imo ako ati aboo yi. Lehin na asi ni awon omo to dagba. Beena l'odun 50, oko ati iyawo ma kuro ni ile won si se irin ajo mimo lati tura lowo ife ebi yi. Bayi ti okurin na bati ni ilosiwaju die asi sofun iyawo re pe " Lo toju awon ebi wa ati awon omo, tonba ti dagba wonsi toju e na. Jekin gba sannyasa." Beena o yeko wa fun ara re kosi se iwaasu lori imoye to ni. awujo Veda leleyi. Konsepe k'okurin joko sile titi digba toma ku. Rara. Ninu Esin Buddha won ni ofin pe awon elesin gbodo gba sannyasi fun odun mewa. Beeni. Nitoripe èrò towa niwipe agbodo gbiyanju lati ni ilosiwaju ninu eto mimo. Beena teyan ba duro sinu ile ebi, pelu idimu towa, kosi bosele ni ilosiwaju ninu eto mimo. Sugbon ti ebi re ba ni imoye Krsna na, iranlowo loje fun. Sugbon eleyi lee lati ri. Nitoripe oko le ni imoye Krsna, ki iyawo ma ni. sugbon asa yi da tojepe gbogbo eyan fe duro sinu imoye Krsna yi.