YO/Prabhupada 0573 - I am Prepared to Talk with any God Conscious Man



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Prabhupāda: Nisin moti ko leta kan si popu. Seyin ti ri? Nibo ni iwe na wa?

Hayagriva: Oun re.

Akoroyin: Oh, leta si popu. So daun?

Prabhupada: Rara, mio ti gba idaaun kankan. So wa ninu awon iwe iroyin? Rara, kosi ninu iwe iroyin yi. Nibo ni eyi to kehin wa? Talo wa nibe? E sofun won kon eyin tose sese jade. E mu eyi tose sese jade wa. Beena asese ran leta yi, sugbon kosi idaaun kankan. Kilode? (Isinmi...)

Prabhupada: Mofe paarapo pelu gbogbo awon eyan sugbon awon eyan wanyi o fe gba. Kini molese? Mofe soro pelu gbogbo awon okurn ninu imoye Oluwa. Eje ka s'eto fun àtòjọ-ètò ki awon eyan bale jeere na, sugbon wanfe se nkan to wu won. T'aba ri wipe taba'n tele esin kan, ale ni ife s'Oluwa, esin t'ipo kini niyen. Sugbon teyan ba nife fun esu lehin na iru esin wo niyen?

Akoroyin: Oto niyen.

Prabhupada: (Erin) Se ri . Idanwo wa niyen. Teyin ba tini... Awa osowipe ema tele awon Onigbagbo tabi Musluman tabi Jew tabi Hindu - awa o sobe. Seyin ti nife s'Oluwa. Sugbon won jiyan, " Oh, Oluwa nimi. Tal'Oluwa? Oluwa nimi." Seri? Wanti ko awon eyan nisin pe Oluwa ni gbogbo won. Seri bose tidi nkan ere. Oluwa nigbogbo wa. Seyin ronu bayi na?

Akoroyin: Seyin ma Meher Baba?

Prabhupada: Asiwere imi tun niyen> Oun lon sewaasu pe Oluwa ni gbogbo wa.

Akoroyin: Osowipe oun gan l'Oluwa.

Prabhupada: Olorun loje. Se tir. Nkan ton sele niyen.

Akoroyin: Seyin mo?

Prabhupada: Moti gbo oruko. Mio tie fe mo iru awon eya bayi. Osin s'rto Oluwa loje>

Akoroyin: Osowipe koi ti soro fun odun marunlelogogji.

Prabhupada: Iyen gan fihan pe aawon eyan o mo eni t'Olorun je. Kasowipe tinba wa bayin pe emi ni Olori Johnson, seyin ma gba?

Akoroyin: Rara (erin) Mio rope mofe gba.

Prabhupada: Sugbon awon asiwere wanyi won si gba pe Oluwa loje nitoripe won o mo eni t'Oluwa je. Asise to wa niyen. Awa mo eni t'Oluwa je, nitorina aw ao le gba were kan ton pe ara re l'Oluwa. Iyato to wa niyen.

Akoroyin: Iranu lasan loje teyan bajade tosi sofun yin pe Olorun loje.

Prabhupada: Sugbon ode gan lon gba pe Oluwa loje. Oun gan lode to gaju. Ole loje ati okurin tosi gba, asiwere imi na loje. Komo eni t'Oluwa je. Enikeni le jade lati sowipe Olorun loje, Olorun tidi nkan to rorun lati ri ninu oja, nibikibi.

Akoroyin: Looto, ninu imoye awon imoye geesi pe Oluwa da eda eyan bosoje, beena Olorun dab'eyan na, nitorina awon okurin leje Olorun.

Prabhupada: Oda bee. Eyin ni awon onisayensi to po gan. E sewaadi lati mo nipa irisi Olorun, boya oni irisi tabi rara... Nipo ni apa ile-ise yi wa? Seyin o ni iru apa yi lati sewaadi. eyin ni awon apa ile-ise to po, apa ero, apa tibi. Nibo ni apa ile-ise yi wa, Tal'Oluwa je? Se apa ile ise yi wa?

Akoroyin: Mio mo... Kosi apa-ile ise kankan ton sewaadi nipa Olorun, toba wa ma sofun yin.

Prabhupada: Isoro to wa niyen. Egbe imoye Krsna yi ni apa-ile ise to wa lati sewaadi nipa eni t'Oluwa je. lehin eyin oni gba awon asiwere wanyi bi Olorun, Olorun nikan lema gba bi Olorun. (Opin)