YO/Prabhupada 0578 - Simply Speak What Kṛṣṇa Says



Lecture on BG 2.19 -- London, August 25, 1973

beena teyin bafe fi ipaari si ibimo ati iku yi, ema bosinu igbadun iye ara yin. e tun a bosinu idimu yi.

nūnaṁ pramattaḥ kurute vikarma
yad indriya-prītaya āpṛṇoti
na sādhu manye yata ātmano 'yam
asann api kleśada āsa dehaḥ
(SB 5.5.4)

" O da bee, fun odun die lara eda yi wa fun, lehin na o ma tan." O da bee. O ma tan sugbon eyin gbodo gba ara eda imi. Eyin gbodo gba ara eda imi nitoripe eyin sini ife okan, igbadun iye ara. Beena itumo igbadun iye ara yi niwipe eyin ni awon ife okan teyin fe gbadun. Beena, Krsna si ni ore-ofe to po gan fun wa, " O da, asiwere yi fe nkan bayi bayi, e fun . O da bee. Didinrin yi fe je igbe. O da e fun l'ara elede." Nkan ton sele niyen, ofin iseda.

Beena imoye yi, imoye Bhagavada-gita yo si wa ni pipe fun awujo eda eyan. Krsna sife ka pin imoye yi fun gbogbo awon eyan, sarva-yoniṣu kaunteya sambhavanti mūrtayaḥ... (BG 14.4). Oun ni baba gbogbo eda, to si fe kan ni ilosiwaju: Awon ode wanyi won jiya, prakṛti-sthāni. Manaḥ ṣaṣṭhānīndriyāṇi prakṛti-sthāni karṣati (BG 15.7). won gbekele irori ogbon won, manah, wonsi lo iye ara won, wonsi tiraka gan. tonba si pada siMi wonle gbe dada, bi ore Mi, ololufe Mi, baba Mi, iya Mi, Vrndavana. Nitorin ni Krsna sen wa. Yadā yadā hi dharmasya (BG 4.7). Nitoripe gbogbo agbaye yi n'sa tele igba iye ara eke yi, nitorina lo sen wa lati fun wa ni itosona, sarva-dharmān parityajya: (BG 18.66) " Eyin asiwere wanyi efi gbogbo igbadun yi sile. Ema ni igberaga pe eyin ti ni ilosiwaju lori eto sayensi. Asiwere ni gbogbo yin. Efi gbogbo isoro wanyi sile. E pada wa bami. Mole funyin ni idaabo." Krsna niyen. Ore-ofe re po gan. Ise kanna ni awon olufokansi Krsna ye kon se. Konsepe kon di alagbara idan. Rara, nkan tafe ko niyen. E so nkan ti Krsna ti so. Lehin na ele di Oluko. Ema so isokuso. Caitanya Mahāprabhu na sowipe, yāre dekha tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa (CC Madhya 7.128). E se iwaasu nipa itosona Krsna fun enikeni teba pade. Lehin na eyin le di oluko mimo. Otan. Nkan to rorun leleyi.

Ese pupo. (opin)