YO/Prabhupada 0579 - The Soul is Changing his Body Exactly as We Change our Garments



Lecture on BG 2.21-22 -- London, August 26, 1973

Pradyumna: Isotunmo - " O Partha, bawo leni to mope emi eda o le baje, koni ibimo, tayeraye , bawo losefe fiku pa enikeni?" " Gege b'eyan sen paaro aso toti gbo fun tuntun, beena l'emi eda sen gba ara tuntun ton fi awon toti darugbo sile." Beena ona imi leleyi la je ko daju.. Nkan to rorun. O le ye enikeni. Vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya. bi awon aso, ewu wa sen gbo, ton ma d'akisa, tawa o le lowon mo, beena asi ma juwon nu lati gba aso tuntun. Beena, emi yi sin paaro ara omode si omo kekere. gege bi omode se ni bata, sugbon toba dagba si ara omo kekere, bata na o le wo lese mo. E gbodo wa bata imi fun. Beena ti omo na ba dagba, asi ni bata imi. Beena emi wa sin paaro awon ara gege b'awa sen paaro aso wa. Vāsāṁsi jīrṇāni. Jīrṇāni, toba ti darugbo, tiko se lo mo, yathā vihāya, asi fisile... Vihaya asi fisile. Navāni, ewu tuntun. Naraḥ aparāṇi gṛhṇāti. Nisin wanti juwe ara eda bi aso. Gege bi ewu ati aso. Aranso asi ge gege bi ara yin seje. Beena, ara eda yi, toba je aso ati ewu, wansi ma ge kobale wo ara emi wa. Ara emi yi o kin se nirakara, laini irisi. Tio ba ni irisi, lehin na bawo ni aso na se l'apa at'ese? Ogbo ori lasan loje. Aso tabi ewu yi l'apa at'ese, nitoripe eni ton lo aso na l'apa at'ese. Beena eleyi fi hin wioe ara eda yi o lese koma ni irisi. Kon se afefe, o ni irisi re. Sugbon irisi yi kere gan, aṇor aṇīyān mahato mahīyān: irisi yi kere ju atomu lo. Aṇor aṇīyān mahato mahīyān. Irisi meji lowa, mimo Ikan je t'Olorun, virāt-rūpa, mahato mahīyān, ati irisi t'awa, aṇor aṇīyān, o kere ju atomu lo. Wanti salaye ninu Kaṭha Upaniṣad. Aṇor aṇīyān mahato mahīyān ātmāsya jantor nihito guhāyām. Nihito guhāyām, towa ninu okan nitumo guhāyām. Awon mejeji wa n'be. Sayensi e sewaadi na. Emi ati emi mimo, awon mejeji wa ninu okan wa. Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe (BG 18.61). Hṛd. Konsepe " Owa nibikibi ara wa." Rara. Hṛd-deśe, ninu okan. looto, sayensi ogun na ti salaaye wipe okan wa ni orisun gbogbo ise wa, ile-ise. opolo wa ni alakoso. Krsn ni olori to wa nibe. Osi so nibo mi pe, sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭaḥ. gbogbo nkan lo daju.