YO/Prabhupada 0588 - Whatever You Want Kṛṣṇa will Give You



Lecture on BG 2.20 -- Hyderabad, November 25, 1972

Beena fun asiko teya ba ni ife okan yi pe " Tinba le dabi Brahma, tabi obam tabi Jawaharlal Nehru," Lehin na mo gbodo gba ara eda yi. Ife okan yi. Krsna si l'aanu to po. Ounkoun teba fe - ye yathā māṁ prapadyante (BG 4.11) - Kṛṣṇa ma fun yin. Lati gba nkan lowo Krsna... Gege bi awon onigbagbo sen gbadura, " O Oluwa, e funwa ni ounje wa lojojumo." Beena se nkan tole loje fun Krsna lati funwa ni ounje wa lojojumo....? Oti funwa. On fun gbogbo awon eda lounje lojojumo. Beena iru adura yi bayi ko loyeka gba. Bi Caitanya Mahāprabhu se so, mama janmani janmanīśvare bhavatād bhaktir ahaitukī tvayi (CC Antya 20.29, Śikṣāṣṭaka 4). Adura leleyi. Awa o gbodo bere fun nkankan. Krsna, Oluwa, ti seto fun itoju wa. Pūrṇasya pūrṇam ādāya pūrṇam evāvaśiṣyate (ISO Invocation). sugbon tawa baje elese awon nkan yi oni wa siwa. Ati di alainigbagbo. Ati d'esu. Lehin na ipese yi ti daduro. Lehin na awa sin sukun. "Oh, kos'omi ojo. Kosi nkan bayi bayi,..." Idaduro lati iseda aye niyen. Sugbon lati eto Oluwa ounje to po wa fun gbogbo eda. Eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. On pese fun gbogbo eyan.

Beena taba ni ife okan lati seto nkan tafe, lehin na agbodo gba ara eda, nkan ton pe ni janma niyen. Bibeko, awon eda o ni ibimo tabi iku. Nisin, janma ati mrtyu yi... Awon eda wanyi dabi ina ton jo, Eledumare si dabi ina nla. Bi ina nla loje. sugbon awon ina kekere yi, ina na lonje. Sugbon nigbami awon ina kekere wanyi man subu lati ina nla wanyi. isokale wa niyen. Itumo isokale yi ni wipe awa ti wa sinu ile aye yi. Kilode? Lati gbadun, lati farawe Krsna. Krsna ni onigbadun to daju. Beena oniranse niwa. Nigbami... Oniranse man rowipe " tinba le gbadun bi oga mi...." ti iru ironu bayi ba de, nkan tonpe ni māyā niyen. Nitoripe awa o le di inigbadu. Eke niyen je. Tinba rowipe mole di onigbadun ninu aye yi gan, Gbogbo eyan lofe di onigbadun. Nkan eke towa nipa awon eyan wanyi nipe, won ma bere sini rope " Nisin moti d'oluwa." Nkan eke ton sele ni. Nialakoko, Mofe d'alakoso, tabi oniwun. Lehin na alakoso ijoba. lehin na toun. ti awon gbogbo nkan ba tan, lehin eyan ma rowipe " Nisin mofe d'Oluwa." Itumo re niwipe iwa yi siwa pe afe farawe Krsna.