YO/Prabhupada 0591 - My Business is to Get Out of these Material Clutches



Lecture on BG 2.20 -- Hyderabad, November 25, 1972

Olugbe India: ...Oṁkāra-svarūpa. sugbon mofe mo tani Siva, Visnu ati Brahma? Se orisa ni awon meta wanyi?

Prabhupada: Beeni. Lat'Oluwa lonti wa. Gege bi ile yi. Lati ile, ema ri awon igi. Lehin ele lo awon igi na latifi danna. Asi yo eefin. Lehin na ina ma jade. Nigbari ina yi ba jade ele fina yi fise nkan teba fe. Beena ikan nigbogbo nkan je..sugbon Lati apeere kanna, ile, igi, eefin, ina Sugbon teyin bafe danna, egbodo lo ina, botilejepe ikan ni gbogbo won je. Beena awon orisa, Brahma, Visnu, Mahesvara. Beena teyin bafe sise egbodo losi ina, Visnu, sattama, sattva-guna. Ilana to wa niyen. Botilejepe ikan lonje, sugbon ele pari ise yin pelu Visnu, awon iyoku ko. Kini ise mi? Lati jade ninu idimu aye yi ni'se mi. Beena enikeni tobafe jade kuru ninu idimu aye yi gbodo gba idaabo Vusnu awon iyoku ko.

Olugbe India: E dakun e sofunmi, kini ife okan yi? Ti awon ife okan wanyi ba kosi basele ni imoye nipa Oluwa. Ife okan na loje teyan bafe monipa Oluwa.

Prabhupada: Awon ife okan aye yi lon so. Teyin ba rowipe olugbe India niyin tojepe ife okan yin ni lati jeki orile-ede yin ni ilosiwaju..... Tabi awon ife okan to po. Tabi eyin je onile. Beena awon ife okan aye yi nigbogbo eleyi. Beena teyin ba wa ninu idimu awon ife okan aye yi, lehin na eyin wa niu ipo aye yi. Lesekee teyin ba rowipe, eyin o kinse olugbe India tani olugbe America, eyin o kin se brahmana tabi Vaisnava, brāhmaṇa tabi kṣatriya, oniranse tayeraye ti Krsna niyin, ife okan to yasi mimo leleyi. Ife okan yi wa nibe, sugbon eyin gbodo yasi mimo. Moti salaye lai pe yi. Sarvopādhi-vinirmuktam (CC Madhya 19.170). upādhi leleyi. Kasowipe eyin wa ninu aso dudu. se iyen wie aso dudu niyin? Tinba bere " tani e?" teyin ba sowioe " Aso dudu nimi" se idaaun to da niyen? Rara. Beena awa ninu aso, aso America, tabi India. Beena teyan ba biyin " Taloje?" Olugbe India nimi" Idanimo tio daniyen. Teyin ba sowipe "Ahaṁ brahmāsmi," idanimo yin niyen. Imoraeni yi loye kani.

Olugbe India: Bawo ni mosefe rigba....?

Prabhupada: Eyin gbodo.. Tapasā brahmacaryeṇa (SB 6.1.13). Eyin gbodo tele awon ofin. Ādau śraddhā tataḥ sādhu-saṅgo 'tha bhajana-kriyā (CC Madhya 23.14-15). Eyn gbodo tele ilana yi. Leyin na eyin ma ni imoraeni yi.

Olugbe India: Sugbon laana oni olufokansi, tofi gbogbo nkan aye yi sile, tolosinu aginju, lati korin oruko Krsna, sugbon osi di yogi. Beena osi bere sini nife fun agbonrin kan. lasiko iku re, osi ranti agbonrin na, ni aye re to kan osi ni ara agbonrin. Beena kosi ife okan kankan, sugbon bakana osi wa bee..

Prabhupada: Rara, ife okan yi wa nibe. On ronu nipa agbonrin yi. Ife okan yi wa nibe.

Olugbe India: Awa sin ronu nipa nkan to po...