YO/Prabhupada 0594 - Spirit Soul is Impossible to be Measured by our Material Instruments



Lecture on BG 2.23 -- Hyderabad, November 27, 1972

beena owa o gba pe nkan wa nitoripe awa o le se isotunmo fun. Awa o leni imoriya nipa nkan mimo yi to wa ninu ara eda wa. Nitoripe gigun and titobi emi wa kosi basele siro re pelu awon ero aye yi, botilejepe awon oni sayensi wan sowipe a le siro re. Beena, boba tiejepe, ala siro re, nialakoko, eyin gbodo mo ibi ti emi yi wa. Lehin na ele gbiyanju lati siro bose tobi to. Nialakoko, eyin o le fojuri. Nitoripe o kere ju ikan ninu egbeerun iwonba eti irun ori wa. Nisin, nitoripe awa o le ri, pelu ogbon lati isewaadi, kosi basele jerisi; Nitorina Krsna ti salaaye nipa emi, wa pelu awon lati fihan nkan t'ei wa o kin se. "Nkan bayi ko loje>" Nigbami t'awa o bale ni oye, wanle salaye pe: " Nkan bayi ko loje." Ti mio bale salaaye nkan to je, lehin na mo le salaaye wipe " nkan bayi ko nimi." Beena kini nkan tio kinse nkan bayi, tiokin se nkan aye yi." Emi wa o kin se nkan aye yi. Sugbon awa ti ni ijerisi nipa awon nkan aye yi. Lehin na awa gbodo ni oye nipa awon nkan tio da? Wanti salaaye ninu ese iwe to kan, pe nainaṁ chindanti śastrāṇi. Eyin o le ge emi wa pelu ohun ijagun kankan, obe, ada, tabi igi. Kolese se. Nainaṁ chindanti śastrāṇi. Imoye Māyāvāda sowipe " Brahman nimi." Nitori aimokan timo ni, mosi rowipe mio parapo mo. Bibeko ikan nimoje." Sugon Krsna sowipe mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7). Beena se iyen sowie latini odindin lonti ge iwonba kekere yi kuro? Rara. Nainaṁ chindanti śastrāṇi. Eyin o le ge si weww. lehin na? Lehin na idaaun to wa niwipe awon emi kekere yi wa tayeraye. konsepe maya loje ka tuke. Rara. Bawo lose je? Nitoripe awa o le ge si wewe.

TInba sowipe... gege bi won se fi awon ijiyan: ghaṭākāśa-poṭākāśa, pe " sanmo towa ninu ikoko ati ofurufu towa nita koko, nitori koko na ni sanma yi se wa nita koko." sugobn bawo lose yato? Eyin o le ge si wewe. Looto iwonba kekere emi yi lawa je. Wansi wa tayeraye. Konsepe nitori awon nkan to sele lawa se tuka lehin na otun parapo. Wonle parapo, sugbon bayi ko, konsepe ale daapo mo ara wa. Rara. Tobatie jepe wan paapo, emi wa ni igbese aye re looto. Gege bi eye towa ninu igi, ole dabipe eye na ti wonu igi, sugbon bayi ko loje. Eye yi sini idanimo re looto. koko oro mi leleyi. Botilejepe eye ati igi na si ni ara alawo ewe, odabipe eye na ti wonu igi, wonu yi, konsepe eye ati igi ti di ikan soso. Rara. Boseje niyen. Nitoripe awon mejeji ni awo ara kanna, nitorina o dabipe eye na o si mo. Sugbon oto oro ko niyen. Beena awon eda loototo niwa. Amuye kanna, kasowipe awo ara wa, nigbateyan ba wonu ina Brahman, konsepe idanimo eda na titan. nitoripe kole so idanimo renu, nitoripe eda na si ni idunnu lokan re, kole se duro sinu ina Brahman yi fun ojo to po. Nitoripe ogbodo wa ibi ti idunnu yi wa. Awon orisirisi nitumo idunnu yi.