YO/Prabhupada 0597 - We are Working Hard to Find out some Pleasure of Life



Lecture on BG 2.23 -- Hyderabad, November 27, 1972

Awon eda aye yi fe nigbala lori iseda. Aisan toni niyen. Ofe ni idari lori ile aye yi. Iranse loje sugbon ofe di Olori aye yi. Aisan towa niyen. Sugbon kole ni aseyori ninu eto lati d'olori aye yi, a si sowipe, "Oh, eke laye yi je. Nisin mofe di nkankana pelu Oluwa." Brahma satyaṁ jagan mithyā. sugbon nitoripe emi wa je nkankanna pelu Krsna, beena, osi ni idunnu. Idunnu yi lon wa. Gbogbo wa lan sise gan lati ni idunnu ninu aye yi. Beena awa o le ni idunnu aye yi ninu ina mimo yi. Nitorina ninu Śrīmad-Bhāgavatam ati gba iroyin pe āruhya kṛcchreṇa paraṁ padam (SB 10.2.32). Sāyujya-mukti. sāyujya-mukti lonpe. Sāyujya, lati di ikan soso. Beena āruhya kṛcchreṇa paraṁ padam. teyan ba tie de ipo yi lati di ikan pelu ina Brahman leyin awe gigba ati inira to po, wansi sokale pada sinu aye yi. Patanty adhah. Atun pada sinu ile aye yi nitumo Adhah. Āruhya kṛcchreṇa paraṁ padaṁ tataḥ patanty adhaḥ (SB 10.2.32). Kilode tonse sokale? Anādṛta-yuṣmad-aṅghrayaḥ. Kosi bonsele gba pe eyan l'Oluwa je. Kosi bonsele gba. Opolo ori wan kekere yi kole ni imoye nipa bi Oluwa se jeyan. Nitoripe oti ni ijeerisi nipa awon elomi, tabi awon iyoku. T'Oluwa baje eyan bi eyin ati emi bawo lose da gbogbo agbaye yi? Nitorina agbodo ni oye nipa Oluwa, sugbon agbodo ni awon iwa rere. Ninu Bhagavad-gītā wan salaye wipe, bahūnāṁ janmanām ante (BG 7.19). lehin igba teyan ba ti so isokuso ninu eto alainigbagbo, teyan ba ti dagba, bahūnāṁ janmanām ante jñānavān, toba ti logbon,... beena kosi bosele ni oye nipa bi otito to gaju se je eyan, sac-cid-ānanda-vigraha... (Bs. 5.1). brahmeti paramātmeti bhagavān iti śabdyate. Bhagavān. vadanti tat tattva-vidas tattvaṁ yaj jñānam advayam (SB 1.2.11). Oro towa ninu Śrīmad-Bhāgavata niwipe : Aown eyan to mo nipa otito mimo wanyi, won mo nipa Brahman, Paramatma ati Bhagavan, ikan lonje. Iyato wa lori ipo nipa oye eto na." gege be eyan toba wo ipata lat'ookan, eyin ba ri awon nkan tio se ri dada/ Teyin ba sunmo si, lehin na eyin mari awon nkan ton ni awo ara ewe. teyin ba sin guke apata na, eyin ma ri awon eranko, igi at'eyan na. Beena, awon tonfe ni oye nipa Eda to gaju lat'ookan, tabi ibi to jina, won ri nkan pelu irori wo, nipa Brahman tio ni irisi. Awon tonba sunmo die bi awon yogi, won le ri eda to wa ninu wa. Dhyānāvasthita-tad-gatena manasā paśyanti yaṁ yoginaḥ (SB 12.13.1). Wanle ri, dhyāna avasthita, towa ninu ara won. Irisi Paramatma leleyi. Awon ton si je olufokansi, won rii Krsna, eleduma re soju,eyan kan sikeji. Nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13).