YO/Prabhupada 0601 - Caitya-guru means Who gives Conscience and Knowledge from Within



Sunday Feast Lecture -- Los Angeles, May 21, 1972

Beena awon agbara Olorun leleyi. Konsepe mole fi agbara idan kan hon lesekese moti d'Oluwa. Eyin na e wo agbara idan t'Oluwa. Ema gba awon Oluwa eke wanyi. Oluwa gbodo se igbara idan to jo t'Oluwa. gege bi awa sen se agbara idan yi, t'an jeki awon ero wanyi fo lori ofurufu. Awa sin jeere to po, awo oni sayensi sin sowipe, " Kos'Oluwa. Emi l'Oluwa, nitoripe emi ni mo da oko afefe yi." kini oko afefe yin teba fi we awon isogbe wanyi? Eni toba logbon asi fun Olorun l'ogo dipo toma fun awon oisayensi tabi alakowe wanyi. Nitoripe oti ri agbara na, aduru agbara to wa nibe. Beena o lagbara to po. Ninu iwe Veda ole ye wa pe, parāsya śaktir vividhaiva śrūyate (CC Madhya 13.65, purport). Ninu Veda, Upaniṣad: na tasya kāryaṁ karaṇaṁ ca vidyate. Oluwa o ni ise kankan se. Na tasya kāryaṁ karaṇaṁ ca vidyate. Na tat-samas cābhyadhikaś ca dṛśyate. Koseni toje egbe re tabi eni to gaju lo. Koseni na. Oluwa ni yen. teyan ban farawe, ton farawe Oluwa, Gege bi asiko tawayi, awon eyan to po lonpe ara won ni Oluwa. Sugbon looto koseni tole farawe Oluwa. Oluwa niyen. Na tasya sama. Egbe nitumo Sama. Adhikasya tabi to gaju. Itumo re niwipe gbogbo awon eyan gbodo teriba. Gbogbo awon eyan gbodo wa labe re. Gbogbo won kere s'Oluwa. Eyan na le lagbara gan, sugbon koseni to je egbe re tabi to lagbara to Oluwa. Iroyin Veda niyen. Na tasya sama adikasya dṛśyate.

Awon eyan pataki na si wa, ton sewaadi lati mo eni to gaju. Awon eyan pataki. Beena awon ise wanyi ti awon eyan pataki yi n'se nipataki Brahma... Oun ni eda talakoko ninu agbaye. Beena oti sewaadi pelu ilosiwaju toni lati mowipe Krsna lo lagbaraju. Īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ (Bs 5.1). Oti funwa ni itosona re. " Krsna l'eda to gaju." Gege b'awa sen joko sibi, awon okurin at'obirin to po wa nibi. Ale sewaadi lati mo eni to lagbara ju. Beena, lati jiyan eyin le gba pe " Eyin le gaju." Sugbon emi ko l'alagbara. Mosi ni akeko mimo temi. Oun na si ni oluko toun. Oun na si ni akeko re. Bayi lo titi de Brahma. Brahma ni oluko wa talakoko ninu agbaye yi, oun lo fun wa ni imoye Veda. Nitorina lonse pe ni baba nla, baba baba, pitamaha. Sugbon oun gan kole se bosefe. Ninu Vedānta-sūtra tabi Bhāgavata wansowipe Brahmā... L'eda talakoko. Kosi eda kankan to siwaju re nigbaton da saye. Beena tinba sowipe oun na ti gba imoye re lat'elomi, ijiyan to ma jade niwipe, " Ta l'eni na tofun ni imoye to ni?" Beena nitorina ni Bhāgavata sowipe, "Rara. Lati Krsna loti gba imoye yi." Bawo?"Lat'okan re." Tene brahma hṛdā. Hṛdā. Nitoripe Oluwa, Krsna sin joko sinu okan gbogbo wa - ninu, gbogbo awon eyan. Osi le funwa ni itosona. Caitya-guru l'oruko re. Eni ton fun wa l'ogbon ati imoye latinu nituo Caitya-guru. Ninu Bhagavad-gita Krsna sowipe, sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭo: (BG 15.15) " Mosi joko ninu okan gbogbo eyan." Hṛdi, " ninu okan" sanniviṣṭo, " Mo joko sibe." Sarvasya. Iwo atemi nikan ko, awon erano, kokoro, eye, Brahma, gbogbo eyan. Sarvasya. Gbogbo eda laye. Beena sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭo mattaḥ: " Lat'emi", smṛtir jñānam apohanaṁ ca, "iranti, imoye ati igbaye." Igbagbe na. Teyin bafe gbagbe nipa Oluwa, asi fun yin logbon lati le gbagbe re tayeraye. Aanu re po gan. Ounkoun teba fe, afunyin logbon, " So fe nkan bayi bayi."