YO/Prabhupada 0614 - We should Be very much Careful, Falldown means a Gap of Millions of Years



Lecture on SB 7.9.1 -- Mayapur, February 8, 1976

Itojo awon orisa bere lati Brahma. Oun ni baba talakoko gbogbo awon orisa ati eda Nitorina lonse pe ni prajā-pati tabi pitā-maha, baba agba, prajā-pati. Oun ni orisun gbogbo nkan. Alaye Darwin, alaye asiwere, pe ko s'aye kankan, sugbon awon imoye Veda ti fi han pe aye to daju wa, Brahma. Lati be ni aye ti bere, diedie lo bere sini wosile, awon idoti aye yi. Konsepe ko s'aye kankan. lati awon aye kekere ni awon eyan ti gunke si aye to gaju. Ijuwe tio daju leleyi. Ijuwe to daju ni wipe lati eda tose pataki ju l'aye yi ti bere, Brahma, prajā-pati. Beena ninu gbogbo oro mimo awon lon wa niwaju, nitoripe eyin o le summo Oluwa ninu ipo aye yin to wosile. Seri bayi? Ijeere iwa ese nitumo Ile aye to kere Ninu ipo bayi eyin o le summon Oluwa. Paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān (BG 10.12). (segbe:) Tal'on soro? Pavitraṁ paramaṁ bhavān. Kṛṣṇa l'eda to se mimo ju, pavitraṁ paramam. To gaju nitumo Paramam. Koseni tole summo Krsna t'eni na ba je elese. Kolese se. Gege bi awon asiwere kan, wonn sowipe, " kosi nkankan towa pelu iru ounje teyin je, pelu nkan teyin se. Kosi idilowo kankan ninu ilosiwaju aye mimo teyin ni." Awon asiwere, awon asiwere wanyi, wan ko gbogbo agbaye ni ikoku ko pe ninu eto imoye Eda to Gaju eyan le huwa kuwa bi awon eyan pelu iwa tio da. Rara. Kolese se. Paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān (BG 10.12).

Beena teyin bafe summon eda to wa ni pipe ju, eyin na gbodo ya si mimo. Bibeko kolese se. Lai d'ina eyin o le wole sinu ina. Lehin o ma jo yin. Beena, botilejepe Brahman leyin na.... Iwonba die ninu Para-brahman na ni Brahman. Ahaṁ brahmāsmi. Idanimo tani niyen. Sugbon iru Brahman wo? iwonba kekere lati Brahman. Gege bi sana ati ina gidi. Ina ni awon mejeji, sugbon sana ni san, ina nla ni ina nla. sana yi o le di ina nla. toba fe d'ina nla o ma subu. ina die to wan'be asi paari. Ti sana yi bafe d'ina nla fun ara re, beena asi paare. Āruhya kṛcchreṇa paraṁ padaṁ tataḥ patanty adhaḥ (SB 10.2.32). Āruhya kṛcchreṇa, pelu awe gbigba ati inira to po, ele gunke si ipo Brahman, sugbon eyin ma subu toba ya. Otooro niyen. Beena, awon eyan to po, won gbiyanju lati wole sinu Brahman to gaju yi, sugbon ibajade to wa niwipe won ma subu. Won gbodo subu sile. Kolese se. Āruhya kṛcchreṇa paraṁ padaṁ tataḥ patanty adho anādṛta-yuṣmad-aṅghrayaḥ (SB 10.2.32). Lai gbiyanju lati s'adura si ese Krsna to dabi ododo, won subu sile. Beena agbodo se jeje kama gbiyanju lati ju Krsna lo. Awon asiwere kan wa ton sowipe " bayi bayi ju Krsna lo." Mio fe daruko won. Awon asiwere wanyi won sowipe " Aurobindo ju Krsna lo." Nkan ton so niyen. Seyin mo bayi? Beena, ile aye yi kun fun awon asiwere at'ode. Agbodo se jeje pel'ogbon lati ni ilosiwaju ninu eto mimo Ema mu oro yi bi ere. Agbodo se jeje. Bibeko ale subu, taba si subu itumu re niwipe aimoye odun to wa. Eyin ti ni ara eda yi lati ni imoye Krsna, sugbon tyin o ba mu eto yi ni pataki, lehin na aimoye odun ti aafo yi je.

Nitorina tāṅdera caraṇa sevi, bhakta-sane vās n'ise wa. Agbodo gbe pelu awon olufokansi ka sise fun awon acarya. Ācāryaṁ māṁ vijānīyān nāvamanyeta karhicit (SB 11.17.27). Eyan gbodo ni oye nipa acarya bi Krsna fun ara re. Ema foju din. Yasya deve parā bhaktir yathā deve tathā gurau (ŚU 6.23). Oro to wa leleyi. Beena agbodo se jeje. gege bi ibi nisin. brahmādaya, awon orisa nla nla, won o le fun Oluwa ni ifokan bale. Inu si bi gan. Evaṁ surādayaḥ sarve brahma-rudra-puraḥ sarāḥ. Awon eyan pataki, rudra, na upaitum. Na upaitum aśakan manyu. Won le fun ni idunnu, ati saṁrambhaṁ sudurāsadam. Sudurāsadam, o si le gan. lesekese ti Krsna ba dawa lebi, o ma le gan lati dide soke. Mūḍhā janmani janmani (BG 16.20). Lat'aye kan sikeji won ma dawa lebi. Ijiya wa leleyi. Beena ema se nkan toma fun Krsna ni ibanuje. E sise fun Oluwa nikan. Nkan to rorun. Man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). E ronu nipa re. E ma ronu nipa elomi,, tabi nkan imi. Sarvopādhi-vinirmuktam (CC Madhya 19.170). Anyābhilāṣitā-śūnyam (Brs. 1.1.11). Egbiyanju lati sise yin lo fun Krsna. Ise wa fun wakati merin le logun, egbiynaju lati se. ema ti segbe kan. Ile aye yin ma ni ilosiwaju.

Ese pupo.

Ajo: Jaya Srila Prabhupada. (opin)