YO/Prabhupada 0621 - Krishna Consciousness Movement Teaches to Become Submissive to the Authority



Lecture on BG 13.1-2 -- Miami, February 25, 1975

Beena egbe imoye Krsna wa yi fe ko awon eyan lati ni igboran si awon olori. Ibere imoye niyen. Tad viddhi praṇipātena paripraśnena sevayā (BG 4.34). Teyin bafe ko nipa awon eto pipe, to koja nkan teyin le fori ro, tele f'ara kan... Itumo irori iranu yi ni ironu, imolara ati iwa tokantokan, Sugbon nkan toba koja nkan teyin le fori ro. Beena Olorun tabi ounkoun nipa Olorun koja irori opolo wa.7 Nitorina agbodo ko nipa awon nkan wanyi dada. Teriba nitumo Tad viddhi praṇipātena, praṇipāta. Prakṛṣṭa-rūpeṇa nipāta. Iteriba nitumo Nipāta. ad viddhi praṇipātena paripraśnena. Ni alakoko e wa eni teyin le teriba fun. lehin na ele bere nipa awon nkan mimo lowo re.

gege bi Arjuna sen se dada. Nialakoko oti teriba si Krsna. Śiṣyas te 'haṁ śādhi māṁ prapannam: (BG 2.7) "Krsna mi, awa sin soro bi ore, lori ipo kanna. Beena teyin ba so nkan emi na ma soro. Bayi awa ma lo asiko wa nilokuko, kode ni siipaari to da. Nitorina, moti teriba si yin bi akeko. Ounkoun teba so, mofe gba." Ipo t'alakoko leleyi. Nialakoko, ewa eni toje pe eni igbagbo ninu re, ounkoun to ba so leyin mase. guru niyen. Teyin ba rowipe eyin da ju guru lo, ko wulo. Ni alakoko ewa eni to daju yin lo. Lehin na ele teriba fun. Nitorina ofin to wa niwipe ema gba guru kankan lai rori wo, awon eyan na o gbodo gba akeeko kankan lai rori wo. Wan gbodo ye ara won wo fun odun kan beena akeko na ma riwipe, " boya mole gba iru eyan bayi bi guru mi," guru na le ni oye pe, " se onitoun yi le di akeeko mi." itosona Sanātana Gosvāmī niyen ninu Hari-bhakti-vilāsa.

Beena nibi Arjuna ti gba Krsna bi guru re. pelu iteriba osowipe prakṛtiṁ puruṣaṁ caiva (BG 13.1). Prakṛti, prakṛti nitumo Iseda yi ati Olori iseda yi nitumo purusa. Gege bi ile aye yi, nipataki ninu awon ilu geesi, wonsi feran awon orile-ede ton sese laju. Nitoripe wanfe losi be lati lo nkan won nilokulo, purusa, Eyin olugbe America eti wa lati Europu lati tun Americ ayi se, awon ilu to lewa, tosi dara gan. Nkan ton pe ni ilo awon ohun ilo aye yi. Beena prakrti,iseda, ati awon eda, nipataki awon eda eyan, purusa niwon. niotoro onigbadun koni wa. Onigbadun eke niwa. Onigbadun ko leje: Kasowipe olugbe America leje. Eti tun ile America yi se dada. sugbon kosi besele gbadun re. Eyin rowipe eyin gbadun, sugbon eyin o le gbadun re. Lehin igba die won ma tiyin jade, " E jade," Bawo leyin se je onigbadun? Eyin le rowipe leyin " odun ogoji tabi ogorun motin gbadun." Beena ele sowipe eyin gbadun,igbadun eke sugbon kosi besele gbadun lo titi na. Kolese se.