YO/Prabhupada 0622 - Those Who are Engaged in Krishna Consciousness, Associate with Them



Lecture on SB 7.6.17-18 -- New Vrindaban, July 1, 1976

teyin bafe gbadun ninuu ile aye yi gan egbodo gba imoye Krsna yi sokan. Krsna ma funyin ni itelorun. Oma fun yin. Kosidi lati se nkan imi fun igbadun ara yin. teyin ba fe... nitoripe awa o le fi igbadun yi sile. Oti mowa lara lati aimoye igba aimoye aye ta ti wa lati gbadun. Kofibe rorun lati fi gbogbo e sile. Nitorina ni awon sastra se sowipe teyin ba tie nife fun igbadun iye ara yin, esi gba imoye Krsna yi s'okan. Ema si nkan imi. Gege bi awon devatas. Wan ni awon nkan elo lati fi gbadun iye ara won. udara-upastha-jihvā (NOI 1) nitumo igbadun iye ara wa, jihva, ahon yi, ikun ati abe okurin tab'obirin. orisun gbogbo igbadun ara eda. Ounje to da, ma jeki ikun wa kun base fesi lehin na ama gbadun imo ako ati abo. Nkan aye yi niyen. Ninu odo metalokan awon nkan wanyi o sin'be. ninu ile aye yi awon nkan wanyi po gan. Beena Prahlāda Mahārāja ti kilo fun awon ore re pe t'awa ba di ifarasi igbadun iye ara wa, lehin na vimocituṁ kāma-dṛśāṁ vihāra-krīḍā-mṛgo yan-nigaḍo visargaḥ. Nigaḍa, orisun nitumo nigaḍa, idi tojepe awa ti gba ara eda yi. Nitori igbadun ara wa. Tato vidūrāt: lati ibi to jina. Tato vidūrāt parihṛtya daityā. " Eyin ore mi tayataya, botilejepe won bi yin sinu ebi awon daitya, ninu ebi kanna lon bimi si" - daitya na ni baba mi. Daityeṣu saṅgaṁ viṣayātmakeṣu: "..." Asat-saṅga-tyāga ei vaiṣṇava ācāra (CC Madhya 22.87). Nkankana. Caitanya Mahaprabhu na tio sobe. Tani Vaisnava? Vaisnava, lesekese loo salaye pe, Vaisnava, kini ise awon Vaisnava? Olufokansi kan bere lowo Caitanya Mahaprabhu pe, " Sa, edakun kini ise Vaisnava?" Beena lesekese lo dauun pelu ila meji, asat-saṅga-tyāga ei vaiṣṇava ācāra: "Lati fi awon eyan ton feran nkan aye yi sile." Eyan le tun bere, " Ta leni to feran nkan aye yi?" Asat eka 'strī-saṅgī: " Eni toba feran obirin, oun ni asat." Ati kṛṣṇa-bhakta āra, " Ati enikeni tio kin se olufokansi Krsna." Beena agbodo fi won sile. Beena ni awon ofin wanyi se wa. Aimase imo ako ati abo. E se igbeyawo, bi okurin jeje, e gba ojuuse yi, leyin na die die e le fi ife imo ako ati abo yi sile. Afi teyin ba fi ife imo ako ati abo yi sile, laini ife okan kankan, kosi besele fi ipaari si iyika ninu ile aye yi - ibimo, iku, ojo arugbo ati aisan. Kolese se. Nitorina Prahlāda Mahārāja ti funwa ni itosona yi, daityeṣu saṅgaṁ viṣayātmakeṣu: "Ema ni asepo pelu won..." Asat-saṅga, nkankana bi Caitanya Mahāprabhu... Asat-saṅga-tyāga ei vaiṣṇava ācāra. Ise Vaisnava niyen. Ema ni nkankan se pelu awon eyan asat, awon eyan ton feran nkan aye yi. ipo to le gan loje. Lehin na lema lese, upeta nārāyaṇam ādi-devaṁ sa mukta-saṅgair iṣito 'pavargaḥ. Nitorina ni ibasepo yi se ...sajjati siddhāśaye. Awon eyan ton sise ninu imoye Krsna, ise ifarasi Olorun, e parapo pelu won. Beena lawa sen gbiyanju lati si awon ile ajosin ninu gbogbo agbaye lati fuin awon eyan laye lati di olufokansi. Base le se si, awa sin fun won ni ile, ni prasadam, awa sin funwon ni itosona, asin funwon l'aye lati s'adura si Krsna. Kilode? Nitoripe awon eyan le gbiyanju lati ni ipaarapo pelu Narayana. Nārāyaṇam ādi-devam, wan le ni ipaarapo pelu Nārāyaṇa. Nārāyaṇam ati gbogbo nkan ninu ise ifarasi fun Nārāyaṇa. Nārāyaṇa, Kṛṣṇa, Viṣṇu, ipo kanna lowa...Nārāyaṇa paro 'vyaktyāt. Nārāyaṇa, eni toni ipo toje pipe, Nārāyaṇa lesekese teyin ba ni asepo pelu Nārāyaṇa, Laksmi ti wa nibe, orisa ola ti wa nibe. Awa o gbadura si awon daridra-nārāyaṇa wanyi ton ti da ara won, rara.