YO/Prabhupada 0634 - Krishna is Never Affected by the Illusory Energy



Lecture on BG 2.28 -- London, August 30, 1973

Nitorina ni Vyāsadeva se ri, apaśyat puruṣaṁ pūrṇam (SB 1.7.4). Gege bi oko afefe, e le fo lori awon sanmo. Awon sanmo o le bo ina orun. Botilejepe labe oko ofurufu yi, sanmo nikan leyin ma ri. Beena kosi bi maya sele se nkankan si Krsna., Nitorina, Bhagavad-gita sowipe daivī hy eṣā guṇamayī mama māyā. Mama māyā (BG 7.14), Kṛṣṇa sowipe, " Agbara aimokan mi." Agbara aimokan yi kole se nkankan si Krsna. Gege bi awon sanmo. Sugbon awon alakowe Mayavadi, wan sowipe nigbati otito to gaju yio ba wa, awon na sini igbagbo ninu aye atunwa, sugbon imoye toni niwipe otito too gaju kole jeyan. Nigbat'oba farahan, asi gba ara maya. Mayadeva leleyi. Oluwa ni Krsna sugbon oti gba ara eda lasan. Beena won fe fi awon eda lasan fiwe Krsna, beena wonle fenu ba Bhagavad-gita je. Wan sowipe avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritam (BG 9.11). Nitoripe Krsna ti wa ninu ara eda lasan.. Irisi re talakoko pel'apa meji. Wan si gbabee na ninu bibeli: Oluwa si da okunrin lati irisi re." Beena apa meji l'Oluwa ni. Irisi re pel'apa merin ti Visnu, irisi t'alakoko ko niyen. Irisi keji lati Sankarsana ni irisi Visnu je. Beena maya o le fowokan Krsna. Nkan to wa niyen.