YO/Prabhupada 0636 - Those who are Learned, they do not make Such Distinction, That it has No Soul



Lecture on BG 2.30 -- London, August 31, 1973

Nitorina, ara eda yi, botilejepe ohun ile aye yi loje, lati orisun kanna, sugbon o si kere beena nigbati dehi, tabi emi wa, botilejepe osi gaju iseda aye yi lo, sugbon, nitoripe o wa ninu iseda aye yi, oti gbagbe Krsna. Ilana towa niyen. Sugbon, wan ti salaaye nibi pe dehe sarvasya (BG 2.30), sarvasya dehe, emi kanna lowa nibe. Nitorina, awon eyan tio ya didinrin, awon eyan ton logbon tonsi ni oye pipe, awon eyan wanyi o lese isasoto kankan laarin awon eda tabi eranko. Paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ. Nitoripe Paṇḍitāḥ loje, alakowe loje, osi mo wipe emi wa nibe. Vidyā-vinaya-sampanne brāhmaṇe (BG 5.18). Ninu ara brahmana, alakowe, emi si wa nibe, emi pel'amuye kana. Vidyā-vinaya-sampanne brāhmaṇe gavi, ninu maalu, hastini, ninu erin, suni - aja nitumo suni - candala, awon eda to woole ju, emi wa ninu gbogbo won. Konsepe awon eda eyan tabi awon orisa nikan lon l'emi, awon eranko o de l'emi . Rara. Gbogbo wa lani... dehe sarvasya bharata. Beena talo yeka gba? Oro Krsna tabi ti awon asiwere alakowe wanyi tabi awon elesin eke? Talo ye ka gbo? Agbodo feti si Krsna, olori to gaju, Eledumare. O sowipe sarvasya. Nibi to po, Krsna sowipe. Nitorina, awon eyan ton keeko, won kin se awon isasoto wanyi, pe kos'emi kankan. Gbogbo wa la l'emi. Tasmāt sarvāṇi bhūtāni. Lehin na, O sowipe, sarvāṇi bhūtāni. Na tvaṁ śocitum arhasi. Ise yin niyen. Krsna si tenu mo oro pe fun tayeraey lemi yi wa fun, kosi besele fiku pa. L'ona to po, eyin ma ri wipe ara eda le paari. "Beena ise re ni lati ja. Eyin le fiku pa ara eda, eyin le ba ara eda yi je. Sugbon na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Sugbon leyin igba teyin ba ti ba ara eda yi je, emi a si wa nibe. Asi gba ara eda imi, otan. " Deha, tathā dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13). Dehāntara-prāptiḥ. Eyin gbodo ni ara eda imi. Won ma salaaye ninu ese iwe to kan.

Fun awon ksatriya ton ja, ogun esin... Ogun esin loye koje. Nkan ton ja fun gbodo je nkan too da. Beena wonle ja. Beena ti ksatriya ba peeyan ninu ogun mimo yi, elese ko loje. Gege bi brahmana. Asi fi eranko fi s'ebo. Iyen o wipe on fiku pa eranko na. Beena, ksatriya, to ban jagun, iwa ese ko niyen. Ama salaaye ninu ese iwe to kan. " Beena ise yin niyen." " Ema ronu wipe eyin fiku pa awon ara ebi yi tabi baba agba yin. Egba idaniloju timon funyin pe dehi, avadhya, kosi besele fiku pa, oma wa tayeraye." Nisin, dehe sarvasya bhārata, oye ke foju si oro to se pataki yi, pe gbogbo awon eda, ara eda yin sin dagba nitori emi to wa ninu e. Ara eda yi le tobi tabi ko kere, kosi nkan to buru. Nitorina ohun elo aye yi sin dagba soke nitori emi to wa ninu e. Konsepe emi wa ti farahan ninu aye yi nitori ipaarapo awon oun elo aye yi. koko oro sayensi leleyi. Oun elo aye yi gbekele emi . Nitorina lonse pe ni oun to kere. Yayedaṁ dhāryate jagat (BG 7.5). Dhāryate, on dagba. Emi yi wa nibe; nitorina, ile aye nla yii wa lori emi yi. Boya emi to gaju Krsna, tabi emi kekere. Awon emi meji lowa. Ātmā ati paramātmā. Īśvara ati parameśvara.