YO/Prabhupada 0651 - The Whole Yoga System Means to Make the Mind Our Friend



Lecture on BG 6.6-12 -- Los Angeles, February 15, 1969

Prabhupada: Gbogbo ogo fun awon olufokansi.

Olufokansi: Gbogbo ogo funyin si Prabhupada.

Prabhupada: Apa iwe?

Olufokansi: Ese kefa.

Olufokansi: " Fun eni toti ni idaari lori okan re, ore re loje. sugbon fun eni tio le se, ota re l'okan re je (BG 6.6)"

Prabhupada: Beeni. Wan soro nipa okan. Gbogbo ilana yoga wa lati so okan wa d'ore wa. Okan wa, ninu ile aye yi... Gege bi amoti, ota l'okan re jesi. Oni ese iwe kan to da gan ninu Caitanya-caritāmṛta.

kṛṣṇa bhuliya jīva bhoga vāñchā kare
pāśatemāyā tāre jāpaṭiyā dhare
(Prema-vivarta)

Okan... Emi nimi, nkankana pelu Eledumare. Lesekese ti okan wa ba ni idoti, ma bere sini huwakuwa, nitoripe moti ni ominiran die. "kilode timo fe sise fun Krsna tabi Oluwa? Oluwa nimi." Okan wa lonsofun wa. Gbogbo nkan wanyi ti yika. Owa labe itanra yi, aimokan, gbogbo ile aye re ti baje niyen. T'awa o ba le ni idari lorio okan wa, tafe ni idari lori awon ijoba nla nla, sugbon tawa o ba le ni idari lori okan wa, lehin na teyin ba tie niidari lori ijoba na, ipadaanu loje. Okan yin l'ota to gaju teyin ni. Tesiwaju.

Olufokansi: Fun eni toti ni idari lori okan re, eyan bayi ti padi emi mimolokan, nitoripe oti ni ifokanbale. Fun irun eyan bayi, idunnu ati ibanuje, oru at'otuttu, ogo ati eebu nkankana nigbogbo e (BG 6.7)."

Prabhupada: Tesiwaju.

Olufokansi: Ale sowipe eyan tini agbara idan tabi odi yogi tabi otini imo nipa ara-eni, nigbato ba ni itelorun ninu imoye ati imo ara-eni. Iru eyan bayi wa lori ipo to gaju, ara re si bale. O le ri gbogbo nkan, boya okuta, tabi wura bi nkankana (BG 6.8)."

Prabhupada: Beeni. Nigbat'okan re ba bale, lehin nani ipo yi ma wa. Okuta, tabi wura, iye kanna.