YO/Prabhupada 0657 - Temple Is The Only Secluded Place For This Age



Lecture on BG 6.6-12 -- Los Angeles, February 15, 1969

Olufokansi: Lati ni adase ninu yoga, eyan gbodo losibi ti awon eyan osi... (BG 6.11)

Prabhupada: Ilana besele ni adase yoga leleyi. Ninu orile-ede yi, adase yoga po gan. Awon egbe eke yoga po gan. Sugbon ilana lati se yoga wa nibi t'Oluwa ti juwe . Tesiwaju.

Tamal Krsna: Eyan gbodo losibi ti awon eyan o si kosi te eni kusa si ilele, lehina ko bo pelu ara agbonrin ati aso to dara. Ijoko yi ogbodo gaju tabi kode gbodo kuru ju, oye ko wa nibi mimo. Yogi na gbodo joko dada sori e ile toda, lehin na ogbodo ni idari lori okan ati iye ara re, fifo okan re kosi fi okan re lori ipo kan."

Prabhupada: Ilana t'alakoko towa ni lati joko ati ibi toye kojoka. Ijoko. Eyin gbodo wa ibi toda teyin le joko kesi se yoga. Ilana t'alakoko niyen. Tesiwaju.

Tamal Krsna: "Alaye: Ibi mimo nibi tele se irin ajo mimo. Ni India, awon yogi, awon eyan mimo tabi olufokansi ma kuro ni'le, kesi wa nibi mimo bi Prayāga, Mathurā, Vṛndāvana, Hṛṣīkeśa, Hardwar, wansi losi lati se adase yoga."

Prabhupada: Nisin, kasowipe eyin gbodo wa ibi mimo. Lasiko tawayi, awon eyan melo lonfe wa ibi mimo. Fun itoju ara re o gbodo wa ninu ilu ti awon eyan ti popju. Nibo leyin fe ri ibi mimo? Beena teyin o ba le wa ibi mimo, lehin na bawo lesele se adase yoga? Ilana t'alakoko niyen. Nitorina, ilana bhakti-yoga yi, ile-ajosin nibi mimo. Ele gbe nibinirguna loje, nkan to gaju. Imoye Veda to wa niwipe ibi ifekufe okan ni ilu je. Nitorina ni aginju seje ibi toni oun rere. Ile-ajosin losi gaju. Teyin ban gbe ni ile, ibi tonu ifekufe to po niyen. teyin o bafe gbe nibi toni ifekufe to po bayi ele losinu aginju. Ibi mimo. Sugbon ile ajosin, ile adura Oluwa, o gaju ibi tole ni ifekufe tabi nkan rere lasan. Nitorina ni ile ajosin se je ibi ipaamo lasiko tawayi. Eyin o le losi ibi ipaamo ninu aginju. Kolese se. teyin ban se igberaga pelu awon adase yoga ninu ile eko yoga, sugbon eyin sin se isekuse, adase yoga ko niyen. Ijuwe nipa adase yoga leleyi. Tesiwaju. Beeni.

Tamal Krsna: Ninu Bṛhan-Nāradīya Purāṇa wan sowipe ni Kali-yuga, lasiko tawayi, nigbati iwon aye awon eyan kere gan, ti awon eto mimo o le dawon loju, tonde ni isoro to po, oan to daju fun imo mimo ni orin kiko oruko Oluwa. Ninu asiko ija ati abosi, ona kan soso fun ominiran ni kiko orin oruko Oluwa. Kos'ona imi fun aseyori."

Prabhupada: Beeni. Ilana towa ninu Bṛhan-Nāradīya Purāṇa niyen.

harer nāma harer nāma harer nāmaiva kevalam
kalau nāsty eva nāsty eva nāsty eva gatir anyathā
(CC Adi 17.21)

Harer nāma, ekorin oruko Oluwa. Ilana kan soso to wa niyenfun imo ara-eni tabi lati le sasaro. Kos'ona imi, kos'ona imi. Awon ona imi olese se. Osdi dara toje pe awon omode gan le se. Nkan fun gbogbo aye leleyi. (Opin)